Ètò Ìjàkadì Ogun Jíjà Tí ÈmíÀpẹrẹ
ỌJÓ 2: Èmí Jésibélì
Èmí Jésibélì wá láti sún wa désè àti pé nígbà mìíràn o máa sisé nípasẹ èkó àti àsọtélè. Èmí máa ń sún àwọn èèyàn mímó sínú ìbọrìsà àti ìfékufèé ara. Èmí náà lè lo ìdarí àti àkóso àti ìmú ṣísé láti ṣe èyí, àmó èyí kìí ṣe ìparí ètè e. Ìparí ètè Jesibeli ní láti pá ní. Ikú ní èrè èsè, àti Jésibélì darí àwọn èèyàn sínú èsè.
Àwọn àlùfáà— tàbí ẹníkeni, níti yen— tón subú sínú èsè àgbèrè pèlú àwon àmì ẹ̀yẹ Jésíbélì. Tí o mbá ṣe ohunkóhun fún Olórun, Jésibélì fé pá ohùn re. Tí Jésíbélì kò bà lè pá ohùn rẹ, o má gbìyànjú láti so ohùn rè dìdàkudà nípa sínsún é láti ṣọ ará e dí elégbin nípa fifààyè gbà àwọn àwọn ìṣe e.
Jésibélì kìí ṣe ohun tí o kàn lè yá lulè lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, àmó o lè kúrò nínú àdéhùn pèlú e àti kí o kò láti fààyè gbà.
Bàbá, Mo ronú pí ìwàdà fún fifààyè gbà Jésibélì mo sí béèrè fún ìdáríjì Yin, ni orúkọ Jésù. Mo bèbè pé kí É wò ọkàn mi sàn láti èyíkéyìí ìrora tí mo mò tàbí èyí tí mi kò mò, ogbé, iṣẹ èsè, ìpalára, ìgbéraga, ìkósílè, ìṣòtè, tàbí èyíkéyìí ìlèkùn tó sí sílè tó lè tí jé kí tàbí tó ti fààyè gbà Jésibélì lààyè sínú ayé mi.
Mo tú isé ajé, àgbàrá ìṣàkóso, àwọn ètàn, òrò dídùn, àwọn òrò èpè, àwọn ìfípákọluni tún báni lérù, ẹ̀sùn èké, àsọjáde alásọtẹ́lẹ̀ èérí, ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ láti súnní désè, iṣẹ́ adáhunṣe, ìkóní láyà je, àti àwọn iṣé rírùn mìíràn tí Jésibélì, ní orúkọ Jésù. Àmin.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Nipasẹ àwọn èkó tó lágbára wónyìí o máa ṣàwarí óye tó jinlẹ̀ lórí bí o máa se ṣèdá ogbón láti gbọn féfé ju àti borí àti sèdíwọ fún ètò òtá rè láti pá ayé è rún
More