Ètò Ìjàkadì Ogun Jíjà Tí ÈmíÀpẹrẹ

Spiritual Warfare Battle Plan

Ọjọ́ 1 nínú 5

ỌJÓ 1: Ìjàkadì Tó Kò Ojú Ogun Ṣi Búburú

Nígbà tí mo ní ìgbàlà, Mo rò pé mo máa lo ìgbésẹ ayé mi ní rìnrìn lẹgbẹ omi tó pároro àti dùbúlè sí pápá oko tútù. Mi o ní oyè pé dídìmò Jésù gégé bí ògákò ìgbàlà mi túmọ sí mo ń forúko sílẹ̀ fún egbé ogun Olórun.

Láti ìgbà náà mo tí kékọọ pé àwọn onígbàgbọ jé ajágun àtìpé Jésù kò mú àlàáfíà wà àmó idá. Mo tí ṣàwarí pé Mo jú aségun lo nínú Kristi, èyí tó tún sọ fún mi pé àwọn aláìwa bí Olórun àti àwọn ìpà tí a kò fojú rí ń gbìyànjú láti borí.

Tójú òtítọ yìí sínú ọkàn rè: òtá wá láti pá, jí, àti pá rún. Gbogbo èmí burúkú yìí ló ní isé ayánfúnni kánnà. Ònà tí wón gbà ṣe—ogbón àti àrékérekè—lo yàtò. Èmí ẹrù máa dójú ìjà kò ìgbàgbọ́ rè, fún àpẹẹrẹ, nígbà tí èmí ìkòtì gbógun já ìdánimò e. Sátánì ní ogbón ìwéwèé. Àwọn ọmọ ogun é tó létòlétò, o ń sin ràn àwọn èmí kánkán lòdì sí àwọn onígbàgbọ láti mú wọn sarán láti ètè ìjọba wọn.

Ádùrá mi ní pé o máa jèrè ogbón láti dá àwọn èmí tó ń takò ayé e mò—àti ayé àwọn tí o féràn— àti pé bí a bá já fáfá ní témì láti jíjà pàdà. Ìgbèkùn témí lè fára hàn ní ònà tó pò, ìròyìn ayọ̀ ní pé ìṣẹgun lè jé tí wa. Nípa rìnrìn nínú àṣẹ tí Olórun fún wa, a lè jíjàkadì àti borí lónà tó múná dóko nínú ogun jíjà.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Spiritual Warfare Battle Plan

Nipasẹ àwọn èkó tó lágbára wónyìí o máa ṣàwarí óye tó jinlẹ̀ lórí bí o máa se ṣèdá ogbón láti gbọn féfé ju àti borí àti sèdíwọ fún ètò òtá rè láti pá ayé è rún

More

A yòó fé láti dúpe lówó Charisma House fún ìpèsè ètò yii. Fún ìsọfúnni síwájú sí, Jọ̀ọ́ bè eyii wò: http://bit.ly/spiritualwarfarebattleplan