Ọjọ́ Mẹ́fà lóríi Orúkọ Ọlọ́runÀpẹrẹ
DAY 2: ELOHE CHASEDDI – p> ỌJỌ KEJI: ELOHE CHASEDDI- ỌLỌRUN ALÁANÚ
Ìgbé ayé kò gbà ẹnikọọkan wà l'áyé láti lò ní ìgbà méjì. Awọn ìgbà míràn wà tí àwọn ìpinnu wà lè má dára tó - yálà nípa ọrọ ti a sọ sí ọrẹ kan, tàbí àṣìṣe tí a ṣe n'íbi iṣẹ wa, tàbí àwọn àsàyàn alàìlera tí a yàn- wọnyi a máà ṣe òkùnfà ohun tí ó l'agbara fún wà. A lè pàdánù ọrẹ. A lè rọ̀wánípò n'íbi iṣẹ. Àìlera lè dé bá wa. Bí a bá tilẹ̀ ní ìyípadà ọkàn, ìdánilójú kò sí pé ohun gbogbo lè padà bọ sípò
Àánu Ọlọrun, síbẹ̀síbẹ̀ ńfún wa ní ohun tí ó jọ ìgbé ayé ẹ̀rẹ̀kéjì lẹhin àkókò kíní ELOHE CHASEDDI- Ọlọrun Aláanú - ńrọ̀jò ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ fún wa O sì wẹ wa pẹlu iṣeun ifẹ Rẹ. O jẹ olootọ sí wa ní gbogbo ìgbà. Òun á máà ṣ'áànú nígbà gbogbo. Ó sì kún fún àánu ní ọjọ gbogbo tí a bá ní ìfẹ Rẹ tí a sì ńtọrọ ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ lọdọ Rẹ. Òun á sí máà fí fún wa nigbakugba
Nítorípé O jẹ Ọlọrun Aláanú, á lè gbé ìgbé ayé laifoya. Ní gbogbo ìgbà ní a sì wà ní àlàfíà àti ifọkanbalẹ tí ó péye tí ó sí nfi fún wa lọfẹ àti lọpọlọpọ pẹlu. O ṣe ìlérí láti wá pẹlu wa nigbakugba àti láti mú wa là ìdààmú àti ipọnju kọjá. Bí ó tilẹ jẹ pé ọdọ wa ní àṣìṣe náà tí w'aiye, O ṣe tán láti d'áríjì ọkàn tí ó bá ronúpìwàdà
Dípò kí á máà ṣe àníyàn nípa ohun tí ó tí kọjá lọ l'ana, Ọlọrun fẹ kí á kíyèsi ohun tí ó ńsẹ́lẹ̀ lọwọlọwọ l'oni. Báwo ní á ṣe lè sìn l'oni? Àwọn ìlànà ètò wo l'oni fún wa láti ṣe àṣeyọrí l'ori wọn l'oni? Báwo ní á ṣe lè jẹ alábapín Rẹ pẹlu awọn míràn l'oni? Ìyẹn ní ó jẹ ẹwà àánu - ni ẹ̀rẹ̀kejì láti fí ojú s'ọ́na, pẹlu idojukọ ọjọ ọlá tí O ní fún wa
OF MERCYLife doesn’t always guarantee us second chances. There are times when our poor decisions—harsh words spoken to a friend, mistakes made on the job, life choices that aren’t healthy—cost us. We lose the friendship. We’re dismissed from our job. Our health suffers. Even if we have a change of heart, there’s no assurance that everything will be okay.
God’s mercy, though, gives us second chance after second chance. Elohe Chaseddi—God of mercy— showers us with forgiveness and bathes us with lovingkindness. He is always truthful. Always merciful. Always compassionate. If we love Him and ask Him for His forgiveness, He grants it. Always.
Because He is a God of mercy, we can live unafraid. We always have access to the peace of mind and heart that He so freely gives in abundance. He promises to always be with us and to bring us through every troubling situation and every difficult season. Even when the mistakes are of our own doing, He is forever willing to offer forgiveness to a repentant heart.
Instead of worrying about yesterday, God wants us to focus on today. How can we serve Him today? What plans does He have for us to accomplish today? How can we share Him with others today? That’s the beauty of mercy—second chances, looking ahead, with a focus on the future He has for us.
Nípa Ìpèsè yìí
Láti inú ọ̀pọ̀lọpọ̀ orukọ Ọlọ́run, Ó ti fi àwòrán dí ẹ̀ hàn wá bí Òun ṣe jẹ́ àti àbùdá Rẹ̀. Ju ìwọ̀n Baba, Ọmọ, Ẹ̀mí Mímọ́ lọ, Bíbélì fi ọgọ́rin ó lé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ orúkọ Ọlọ́run hàn. Ẹ̀kọ́ yìí ṣe ìtọ́ka sí mẹ́fà àti ìtumọ̀ wọn láti ran onígbàgbọ́ lọ́wọ́ láti sún mọ́ Ọlọ́run Olóòtítọ́ kan ṣoṣo. Àyọkà láti inu ìwé tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́, Experience the Power of God's Names: A Life-Giving Devotional (Níní Ìrírí Agbára Orúkọ Ọlọ́run: Ẹ̀kọ́ Wíwá Ojú Ọlọ́run ti n Fún ni Ní Ìyè), làti ọwọ́ Ọmọwé Tony Evans. Eugene, tàbí: Harvest House Publishers, 2017.
More