Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ

Kristi Imole t‘o da wa sile

Ọjọ́ 6 nínú 7

Kristi, Ọna Sí Ìṣẹgun

Ọnà abayọ wa ni gbogbo igba fún ipò tó nīra. Ko sí iṣoro rí tíó ní ọnà abayọ ti atí pèsè, kikidã ki àwarí ni.

Jésù kede rẹ wipe

"...Emi li ọ̀na, ati otitọ, ati iye: kò si ẹnikẹni ti o le wá sọdọ Baba, bikoṣe nipasẹ mi." Jòhánù 14:6.

Ọnà Ọlọrun ni apẹrẹ jẹ ọnà tí otọ ni gbogbo igba ti oṣe lòdì sí iwa ika, irira ati ti o lòdì sí òfin. Titẹle ọnà tí otọ lati kúrò ninú iṣoro amã fun ọta ni agbára lori rẹ, maṣe eleyii. Jẹki Kristi jẹ imọlẹ itoni rẹ.

Kristi yíò kọọ, yíò darí rẹ nipasẹ Ẹmi mimọ ti obá dúró dē.

Oluwa tan ìmọ́lẹ̀ Rẹ̀ s'ori gbogbo ipò inira ki osi fúnmi ni iṣẹgun pátápátá ní orúkọ Jésù.

Ìwé mímọ́

Day 5Day 7

Nípa Ìpèsè yìí

Kristi Imole t‘o da wa sile

Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL