Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ
Tẹle Imọlẹ Na
Ni ibiti òkùnkùn bati njọba ayé ẹru, ibẹrubojo àìdániloju, inira ọkan yíò ṣi silẹ. Jesu kéde rẹ wípé "Emi ni imọlẹ Àyè" bẹni, Òun ni Ọrọ Atetekoṣe ti o wa pẹlu Ọlọrun ti osi jẹ Ọlọrun...Ninu rẹ̀ ni ìye wà; ìye na si ni imọlẹ̀ araiye.
Imọlẹ na si nmọlẹ ninu òkunkun; òkunkun na kò si bori rẹ̀. Johannu 1:1,4-5
Jésù Òdà ẹnu dúró níbẹ ṣugbọn ọtun wípé àwa Kristẹni "Ni imọlẹ Àyè" Matthew 5:14, nipa gbigbãgbọ ati titẹle, àdí onirohin imọlẹ titi dé òpin Àyè. Nipa èyí akiyõma gbé labẹ ide ati ipọnju ẹru.
Ti o bà tẹle Jesu to jẹ "imọlẹ Àyè" iwọ na yíò le sọpe " Tali emi o bẹrù"
Jesu Oluwa Funmi ni Òmìnìra ki o si pamimọ̀ kúrò lábẹ́ ìdè ẹru.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL