Kristi Imole t‘o da wa sileÀpẹrẹ
![Kristi Imole t‘o da wa sile](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49813%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Tẹle Imọlẹ
Òun to ṣe pàtàkì jù gẹgẹbi oun awakiri fún ẹni tí o wa nínú okunkun ni imọlẹ.
Ni atetekọ̀ṣe ayé wà nínú òkùnkùn pátápátá ki Ọlọrun to da imọlẹ Genesis 1:2-3
Ni ibiti imọlẹ bàwa, ìgboyà a wa nínú ohunkohun ti eniyan ba nṣe. Kosòhun to nīra tó sì bani lẹru bi ki ènìyàn ma ṣiṣẹ ninǔ agbègbè okunkun.
Woli Eliṣa ni imọlẹ (nipa ìfihàn) pe awon ógun ọrun yi òun ká, nítorí bẹ́ ẹ̀ ru awọn ọmọ ogun Siria ko bã. 2 Kings 6:16-17
Bi òní Psalmu jeki Kristi Jésù jẹ ohun àkọkọ nínú afojusun rẹ, yíò tan imọlẹ sí gbogbo ibi Okunkun ayé rẹ.
Oluwa Funmi ni ọkan toti pinu lati ma wà ọ saaju ohun gbogbo.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![Kristi Imole t‘o da wa sile](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F49813%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Fun gbogbo àkókò òkunkun - ibẹrubojo ati sáà ìyè meji, àkò le ṣe alaimanilo imọlẹ gidgidi ni oniruru ọna. Láti fún wa ní Òye nípa ipò tí a wá tabi ọgbọn fún ìyípadà ilakọja ti ko dára fún réré. Eleyi ni jesu wá sí ayé láti musẹ. O sọ nínú ọrọ iṣẹ rẹ wípé "Emi ni imọlẹ aiye; ẹniti o ba tọ mi lẹhin kì yio rìn ninu òkunkun Johanu 8:12.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Adeoye Gideon fún pípèsè ètò yìí. Fún ìsọfúnni síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL