Gbígbé Nípa Ti Ẹ̀mí Mímọ́: Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì Pẹ̀lú John PiperÀpẹrẹ
Èmí Mímọ́ Kún Wa Pẹ̀lú Ìdùnnú
Fara balẹ̀ wò yíká bí ó ń ṣe rìn, kì í ṣe bí àwọn aláìlógbọ́n àmọ́ bí ọlọ́gbọ́n, lilo àkókò tí a bá ní dáradára, nítorí búburú ni àwọn ọjọ́. Nítorí náà má ṣe jẹ́ omúgo, àmọ́ lóye ohun tí ìfẹ́ Olúwa jẹ́. Àti má ṣe mu wáìnì ní àmuparanítorí èyí je ìwà wọ̀bìà, àmọ́ kún fún Èmí Mímọ́. —Éfésù 5:15-18
Kí nìdí tí àwọn ènìyàn fi ń do yíjú sí ọtí? Fún wákàtí ayọ̀ kan. Gbogbo wa lọ fé ayọ̀, àmọ́ ìṣòro kan wà: “Búburú ni àwọn ọjọ́” (v. 16).
Níbo lọ ń yíjú sí nígbà tí àwọn ọjọ́ bá jẹ́ búburú, nígbà tí jìnnìjìnnì bá bo e tàbí ìrẹ̀wẹ̀sì tàbí depressed tàbí ṣàníyàn? Pọ́ọ̀lù rọ̀ wa: “Máa ṣe yíjú sí ọtí; yíjú sí Ẹ̀mí Mímọ́.Ohunkóhun tó bá ṣeyebíye tí ọtí lè mú wá fún o, Ọlọ́run Ẹ̀mí lè mú jú bẹ́ẹ̀ lo.”
Àwọn ènìyàn wà tí wón kò lè máa bèrè sí ní súfèé ohùn orin tàbí kọ orin lenú iṣẹ́ nítorí wọn wà tẹ ṣe gidigan àti wón se àníyàn nípa ayé. Àmọ́ nígbà tí ó di alẹ́ ọjọ́ yẹn pẹ̀lú ọtí bí mélòó kan tí wón ń mú wón lè fọwọ́ kọ́ ara wọn lọ́rùn àti korin àti rẹrìn.
Gbogbo wa lọ ń hàn hàn fún ṣíṣe ìfẹ́ tára kálukú, kò ìdílọ́wọ́ fun kan, àti láyò. Àti ìbánúje tó ń borí tí ọjọ́ wa, bí ní ti Pọ́ọ̀lù, ní pé nọ́ńbà àwọn ènìyàn tó ń gókè (pàápàá àwọn Kristẹni) gbàgbó pé ọ̀nà kan ṣoṣo láti rí irú òmìnira bí ti ọmọdé yìí ni rò ara wọn pẹ̀lú ọtí. Irú ìwà yìí tàbùkù sí Ọlọ́run, àti pé Pọ́ọ̀lù sọ wípé: Ònà tó dára wà láti fara dà á pẹ̀lú àwọn ọjọ́ búburú—kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, àti pé ìwọ yóò mò ìdùnnú tí kò lè gbé tó ń kọrin àti ṣe orin atunilára sí Olúwa.
Nítorí náà, kí lọ túmọ̀ sí láti kún fún Ẹ̀mí Mímọ́?
Ẹ̀mí tó kún wa pẹ̀lú Èmí ìdùnnú tó ń ṣàn títí láé láti láàárín Ọlọ́run Bàbá àti Ọlọ́run Ọmọ nítorí inú dídùn tí Wón ní sí Ara Wọ́n. Torí náà, to láti kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ ni lati há sínú ìdùnnú tó ṣàn láàrin àwọn the Mẹ́talọ́kan àti láti fẹ́ràn Ọlọ́run Bàbá àti Ọlọ́run Ọmọ pẹ̀lú irú ìfẹ́ tí wọn fi fẹ́ràn ara wọn gangan.
Ojú ònà ti Èmí Mímọ́ ṣe àfonífojì igbó kìjikìji àwọn àníyàn wá sínú síse kedere ìdùnnú ni ojú ọ̀nà ìgbàgbọ́. Ní ìbámu pẹ̀lú Pọ́ọ̀lù, ọ̀nà láti kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ ni nípasẹ̀ gbigbékélè pé Ọlọ́run ónírètí jọba lóòótọ́ —kì í ṣe ológoṣẹ́ tó ṣubú lulé láìsí ìfẹ́ Rè (Mátíù 10:29)—àti pé ó sáré kárí ayé fún ọ àti gbogbo àwọn tó gbékélẹ̀ who ọ̀rọ̀ Rè ọ. Níni ìgbàgbó nínú yẹn, wà kún fún Èmí Mímọ́ àti ìdùnnú.
Kọ́ ẹ̀kọ́ síi: http://www.desiringgod.org/messages/be-filled-with-the-spirit
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Èkọ́ Àṣàrò Bíbélì Méje látọwọ́ John Piper nípa Ẹ̀mí Mímọ́
More