Gbígbé Nípa Ti Ẹ̀mí Mímọ́: Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì Pẹ̀lú John PiperÀpẹrẹ

Live By The Spirit: Devotions With John Piper

Ọjọ́ 7 nínú 7

Èmí Mímọ́ Jí Ara Wa Díde

Tí Èmí òun tó jí Jésù díde kúrò nínú okú ń bá gbé inú yìn, Òun tó jí Jésù díde nínú okú máa tún fún ara kíkú yìn ni èmí nípasẹ̀ Ẹ̀mí tí ń gbé inú yìn. —Róòmù 8:11

Bìkítà Ọlọ́run jínlè pẹ̀lú ara wa. Tí kò bá jẹ́ béè, o máa jé kí o jẹrà nínú ibojì àti so fún o à-kú-tún-kú e. Àmọ́ kò sọ bẹ́ẹ̀ láè. Bẹ́ẹ̀ kò, Ọlọ́run dà e pẹ̀lú ara àti pé o dà o fún ògo Rè.

Torí náà O máa jí o dìde àti fún ẹ̀mí sí ara kíkú rè nípasẹ̀ Ẹ̀mí Rè kò sí bí ó máa ṣe kọminú to, tàbí abirùn, tàbí rù kan egungun, tàbí àrùn bájà, àtipe o máa jẹ́ kí o lókun gidigidi, ìlera dáadáa, yóò rẹwà gidi gan, tí o jé pé tí mo bá rí, Má sọ wí pé, “O dà bí ojú sanmọ aláwọ̀ búlúù gbòòrò tí ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn. O dà bí ọlọ́láńlá mílíọ̀nù ìràwò tó tán yóò ní òkùnkùn biribiri ni gbalasa òfuurufúà àgbáyé. Títànyòò bí òòrùn; béè ní,nínú rè titọ́bi lọ́ba tí ògo Jésù tó dà o, rà o padà, jí o díde, àti fún o lógo pẹ̀lú ogo Rè títí ayé àti láé.”

Níbo ni ènìyàn lè tí rí agbára láti tẹ̀ síwájú ni ayé ìfẹ́ nígbà tí èrè ayé díè lo wà? Níbo ni ọkọ tàbí aya se gba okun ìmọ̀lára láti máa báa lonígbà tí kò se bákan náà? Níbo ni ọkùnrin tàbí obìnrin tó má fé láti se ìgbéyàwó gba okun láti ni ìtẹ́lọ́rùn àádọ́rin ọdún seventy years of aláfọwọ́kọ? Níbo ni Jésù ti lókun láti fara dà àgbélébùú àtipe o tẹ́ńbẹ́lú ìtìjú (Hébérù 12:2)?

Nítorí ìdùnnú tí a gbé ka iwájú rẹ̀ níwájú wa ni àjíǹde a fara dà gbogbo ohun fún Kristi. Jésù kò ṣèlérí pé ìgbọràn sí Òun máa ní èrè látọ́wọ́ ènìyàn ní ayé yìí. Ìdùnnú wa ń ṣàn láti ìrètí tí kò fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin tí Róòmù 8:11, kì í se láti àwọn ipò tó ń yí padà ayé wa. “Tí Èmí òun tó jí Jésù díde kúrò nínú okú ń bá gbé inú yìn, Òun tó jí Jésù díde nínú okú máa tún fún ara kíkú yìn ni èmí nípasẹ̀ Ẹ̀mí tí ń gbé inú yìn.”

Tí o bá gbàgbó pé Ọlọ́run mbè fún e pè Kò sí lòdì sí e, àti pé Yóò fi ẹ̀mí sí ara kíkú e nípasẹ̀ Ẹ̀mí tí ń gbé inú yìn, àti pé ohunkóhun tó dára tí o jọ̀wọ́ sílè ni ayé yìí a yóò sàn padà fún o ni ìlópo ọgọ́rùn-ún àjíǹde àwọn olódodo (Lúùkù 14:12-14), àti pé ìwọ yóò tàn yòò bí òórùn ni ìjọba Bàbá e, nígbà náà ìwọ yóò ní àgbájọ okun tí kò lè tan láti máa ṣé dára dára tí Ọlọ́run ti pè e láti se bóyá ẹnikẹ́ni mọrírì e nísinsìnyí tàbí wón kò mọrírì e.

Kọ́ ẹ̀kọ́ síi: http://www.desiringgod.org/messages/the-spirit-will-give-life-to-your-mortal-bodies

Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Live By The Spirit: Devotions With John Piper

Èkọ́ Àṣàrò Bíbélì Méje látọwọ́ John Piper nípa Ẹ̀mí Mímọ́

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ John Piper àti Desiring God fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú sí i, jọ̀wọ́ lọ sí: http://www.desiringgod.org/