Rúútù, Ìtàn ÌràpadàÀpẹrẹ
![Ruth, A Story Of Redemption](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F2438%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Dídá Yàtò
Lónìí a bẹrẹ láti ríi ìpèsè àti ètò Ọlọrun ni íṣe bí Rúùtù ti bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé tuntun rẹ ní Bethlehemu. O lè fojúinú wò kí o jẹ́ Rúùtù? Ó jẹ́ opó láti ilẹ̀ òkèèrè tí a kò bọ̀wọ̀ fún. Ó jẹ onígbàgbọ láìpẹ́. Ohun gbogbo jẹ tuntun àti àìmọ sìí. Ó dá mi lójú pé ó ṣì ń ní ìbànújẹ́ nítorí íkú ọkọ rẹ̀. Ṣùgbọn nípasẹ gbogbo rẹ àti pèlú gbogbo ẹdun, o di ìgbẹkẹlé tí ó ní nínú Ọlọrun mú ṣinṣin.
Ní ìbẹ̀rẹ̀ orí keji, Rúùtù lo ìdánúṣe láti lọ sí oko kan kó sì pèéṣẹ́ kí ó lè gbé oúnjẹ sórí tábìlì. Gẹ́gẹ́ bí Òfin Léfì ( Léfítíkù 19), a pàṣẹ fún àwọn olùkórè pé kí wọ́n má ṣe pèéṣẹ́ gbogbo pápá náà, ṣùgbọ́n kí wọ́n fi àwọn igun náà sílẹ̀ fún àwọn tálákà. Kì í ṣe pé Rúùtù jáde lọ ṣe iṣẹ́ àṣekára kíkó ìràlèrálè jọ nìkan, ṣùgbọ́n ó jẹ́ ohun tí ó reni sílè jojo.
Ó kan Bóásì, Olùràpadà! Bóásì ṣàpẹẹrẹ Jésù Krístì jákèjádò ìwé yìí, Olùràpadà wa. Àwòrán ẹlẹwaa ti Jésù bí ó se n mú ẹlẹṣẹ wá sí apá ifẹ rẹ. Nítorínà tani ọkunrin yìí tí à npè ní Bóásì? A mọ̀ pé ó ní ìbátan nípa ìgbéyàwó pelu Náómì. A mọ̀ pé ó jẹ àgbàlagbà ènìyàn tí ó se pàtàkì tó sì l'ọrọ ní agbègbè re. Orúkọ rẹ gangan tumọ sí "agbára." A mọ̀ pé ó tọju àwọn oṣiṣẹ rẹ dára dára àti àwọn àlejò dáradára. Ní pàtàkì julọ, a mọ̀ pé ó jẹ ènìyàn Ọlọrun.
Lẹ́yìn tí Bóásì ti rí Rúùtù nínú pápá rẹ̀ tó sì béèrè nípa rẹ̀, ó sọ fún un pé kó dúró nínú pápá òun, ó sì rí i pé òun ti tọ́jú rẹ̀. Bí Rúùtù se gbo Oro yí, ó wole ó sì bèèrè ìdí tí Bóásì se se òhun láànúú. Rántí pé ará Móábù ni Rúùtù, síbẹ̀ Bóásì ṣe síwájú àti ré kọjá fífi àjẹkù sílẹ̀ fún un.
Bóásì fo èsì tí ó rewa sí ìbéèrè Rúùtù. Kì í ṣe pé Bóásì mọ ẹwà inú àti ìhùwàsí Rúùtù nìkan, ó tún bù kún.
Olorun nfe láti mú gbogbo wa - àlejò, tálákà, àwọn àdásò, àwọn tí won ní ìsòro, àwọn tí won ní ìkorò, gbogbo wa - labẹ àwọn iyẹ Rẹ. Ó nfé láti dáàbò bò ó. Láti fún ọ ní ìtùnú àti ayò. Ìfẹ́ tí Bóásì ní fún Rúùtù jẹ́ àwòrán ìfẹ́ Ọlọ́run fún wa. Pé kí gbogbo wa rí ìsimi àti ibi ààbò lábé apá Re. Ọlọ́run fẹ́ dáàbò bò ẹ́, Ó sì fé kí o dàgbà di ẹni tí Ó dá ọ láti jẹ́.
Nígbà tí Rúùtù pa dà sílé sọ́dọ̀ Náómì, ó kó oúnjẹ tí ó pọ̀ ju bó ṣe rò lọ. Díè nínú àwọn ọjọgbọn gbàgbó pé Rúùtù padà s'ílé pẹlu ounjẹ tí ó tóo je fún ọdún kan! Orẹ, lónìí o le máa wá àwọn àjẹkù ti ìrètí tàbí ìwòsàn, ṣugbọn Ọlọrun fẹ láti fún ọ ní pupọ síi! Fojú wò pé Ọlọrun yíò pèsè fún ọ ju ohun tí o lè nírètí fún tàbí fojú inú wo!

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![Ruth, A Story Of Redemption](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F2438%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Àwọn díẹ̀ ni a lè fi taratara f'ojú jọ nípa ìlàkọjá wọn nínú Bíbélì bíi Rúùtù; tálákà, òpó àtọ̀húnrìnwá tí o fi Ọlọ́run ṣíwájú tí o wá ń wò bí Ó ṣe yí ayé òun padà. Bí o bá ń wá kóríyá nínú àyídáyidà rẹ, má sa láì ka ẹ̀kọ́ yìí!
More
A fẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Brittany Rust fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ sí, jọ̀wọ lọ sí: brittanyrust.com