Sísọ Ọ̀rọ̀ ÌyèÀpẹrẹ
Ìkànnì Ìbánidọ́rẹ̀.
Mi o lè parí ètò Bíbélì SỌ̀ ÈMÍ yìí láìsòrò lórí ayé Ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ tí a ń gbé nínú rè. Ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ ní ipa NLÁ lórí àwọn èrò wa àti, nítorí náà lórí àwon ọkàn wa. Èyí ń ṣàkóso orísun àgbáwolè. Se o tí gbé dára dára anfààní tó fúnni níyè tí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ yèwò dípò búburú àti èyí tó ń àti pańpé ìparun tó sábà máa ń jé?
Òpòlopò ènìyàn lóde òní jìyà lówó àníyàn àti ìsòríkọ̀. Mo nígbàgbó pé a lè wà pàdà séyìn sí púpò lápòjú àgbáwolè búburú àti bákan náà ìwònba àkókò tó fúnni lémi ní isèdá tàbí òrò Olórun. Bóyá TV rè ni, aṣàmúlò FB rè, aṣàmúlò Twitter rè tàbí aṣàmúlò Instagram rè, o ní láti sáyẹwò àkókò tó ń lọ lójú ọgọwú ẹ̀rọ. O máa yá òpò lénu láti máa òye wákàtí tí a ń lọ níwájú pẹ̀lú ojú ọgọwú ẹ̀rọ. Máa ṣe sí mi gbó. Mo gbàgbọ́ pé àwọn àwòrán àti àwọn fídíò, ìsofúni àti wà a làròówotó tó fúnni lémi. Àmó, fi gbọ̀ọ̀rọ̀, a ń kún ọkàn wa pẹ̀lú òpò ìdòtí, ìgbéra ení lógò, àti aláfẹfẹyẹ̀yẹ̀ nípasẹ òpòlopò àgbáwolè búburú. Òpò lára wa jé àlàímokàn sí ìbátan láàrín àkókò níwájú ọgọwú ẹ̀rọ àti ìsòríkọ̀. Òpò lára kò pé ságbéyẹ̀wò pé ÀGBÁWOLÈ jé òùnfà ÀBÁJÁDE. A kò ní láti bíkíta nípa àwọn èrò ẹnikẹ́ni mìíràn, tí Olórun nìkan.
Ayé yìí, àwọn ìròyìn àti ipò wa lè mú wa nímólárá bìí pé a ń rìn aṣálẹ̀ tàbí ní ilè gbígbé. Àwọn ọkàn wa poùngbe fún ìyè àti pé a gbódò fún wọn ní oúnjẹ tó fúnni níyè.Àwon Òrò Rè. Isèdá Rè. Àjọṣepọ̀ Rè. Ṣe o nímólárá ìsòríkọ̀ láti máa rìn jù lórí aṣálẹ̀ tàbí ilè gbígbé ìkànnì àjọlò àti àkókò lójú ọgọwú ẹ̀rọ? Wa sódò omi ìyè kí o jé Kí o satisfy your ọkàn re. Pa àwọn ọgọwú ẹ̀rọ àti sí Òrò Olórun. Sọ pé Kò pàdé é níbè àti sò Òrò Rè èmi. Léyìn náà jáde lọ síta. Rìn lọ rìn bö. Máa ta káìtì. Kàwé tó dára. Bá òré to'n fúnni níyè pàdé.
Ṣe mo lè pé o níjà láti sábáàtì ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀? Gbàdúrà nípa ìgbà tí o máa ṣe èyí àti léyìn ìgbà náà ṣètò oyè àkókò. Yóò dá bí onírúrú àáwe. Léyìn náà, tí o bá nímọ̀lára pé sábáàtì se anfààní, ṣe àdéhùn láti din ìpàdábò rè si ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ kù. Máa ronú lórí gbígbé ìsofúni ìgbérasọ tàbí tó dá lórí Kristi- nìkan jáde. Nígbà tí o jé pé ìpínyà púpò mbè ní orílè èdè wa, ṣe ìpinnu pé wa mú ohun tó máa gbéra wọn ró, níṣìírí àti sò ìyè sínú ayé tó tí pálára. Ayé lè túbọ̀ rọrùn sí í àti láìní ìyonú. A lè ní òpòlopò ìrètí. A ní láti lọ àkókò tá fi wa lójú gọgọwú ẹ̀rọ tán kà nípa àwọn ohun tí kò ṣe pàtàkì àti pé kí a lọ fún àkókò pèlú ẹni tó ṣe pàtàkì.!
Tí o bá fé gbé ayé, so ìyè àti fún ìyè kíkún, nígbà náà o gbódọ̀ ṣàwarí IDÁÁSÍ àwọn ojó rè. Ṣàyípadà àgbáwolè rè, ṣàyípadà àbájáde rè. Àwọn ojó wa jé kúrúkúkúrú. Bèrè NÍSÌSIYÌÍ.
Gbà èyí wò: Báwo ni o se lè ṣàyípadà láti dínkù tàbí mú àkókò tó ń lọ lójú gọgọwú ẹ̀rọ ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ rè kúrò? Kíni àwọn ohun tó wúlò tó lè ṣe pèlú àfikún àkókò rè?
Ádùrá: Oh Olúwa! É ràn mí lówó láti pààlà sí àkókò tí mo ń lọ níwájú gọgọwú ẹ̀rọ àti àlékún àkókò mi pèlú Yín. Mo fé gbé nígboyà àti sọ̀ èmí sínú ọkàn àwọn ẹlòmíràn. Mo mò pé o bèrè pẹ̀lú mi.
__________________________________________________________________
NOOTI ÌPARÍ ÈTÒ: Ifẹ Roxanne ni lati sọ awọn òtítọ ti o funni ni èmí sinu ọkan awọn ẹlòmíràn. O nífẹẹ lati s'ọrọ ni àwọn padasehin ati awọn àpéjọ. O gbalejo awọn idanilékòó Idaniloju tó jìnlẹ̀ ati ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn alágbára jakejado orílẹ-èdè bi olúkòi ìgbésí ayé ti ara ẹni. O lè kési àti gbà ìsofúni ní síiRoxanneParks.com. Inu re yoo dun lati ba o soro.
Nípa Ìpèsè yìí
Ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀, àwọn ọ̀rọ̀ tó kún fọ́fọ́ fún agbára! Àwọn ọ̀rọ̀ tí ń múni ró tàbí èyí tí ń fani lulẹ̀. Àwọn ọ̀rọ̀ tí ń fúnni ní ìyè tàbí èyí tí ń mú ikú wá. Èyí tí o yàn wá kù sí ọ lọ́wọ́. Ẹ jẹ́ ká jọ ṣe àgbéyẹ̀wò agbára inú àwọn ọ̀rọ̀ tó ń tẹnu wa jáde.
More