Sísọ Ọ̀rọ̀ ÌyèÀpẹrẹ

Speaking Life

Ọjọ́ 5 nínú 6

Àwọn Ọ̀rọ̀ tí Yóò Tọ́ Ìgbésí-ayé Wa

Níwòn bí ọtá ti ń paró fún wa, a ní láti ṣe ìpinnu láti sò agbára àti òtító pàdà sí í! A ní láti gbé ìgbésè ìse láti fòpin sí àwọn òrò tí kò dára àti àwọn èrò. A nílò ÀWỌN ÒRÒ TÓ KÚN FÚN AGBÁRA LÁTI FÍ GBÉ AYÉ. Àti pé nígbà náà a ní láti máa sọ wón léra léra máa fi dé ọkàn wa àti àwọn èrò wá.

Ohun tó jé òtítọ jù lọ nípa mi nígbà gbogbo ní ohun tí Olórun sò nípa mi…kìí se ohun tí mọ nímólárá tàbí tí mo rò àti àwọn ohun tí àwọn ẹlòmíràn sò, rò tàbí se…. Jìnnìjìnnì lè bọ wa nípa tí ara látówo àwọn ìrò àti ìgbàgbọ́ èké tó jé pé a lè pàdánù ètò dídùn Olórun níwọ̀n ẹsẹ̀ bàtà ẹgbẹ̀rún. Kékòó Òrò Rè. Jé kí ìgbàgbọ rè sòrò àti nígbà náà bí Olórun láti ràn é lówó pé pèlú àìnígbàgbó kánkan.

A ní láti ṣe a ìfárajìn ọtún ọtún láti dẹkùn àwọn òrò tí a ń sò sí ara wa tí kò dára. Bí èyíkéyìí olóró bí èyíkéyìí ìwà búburú, o lè pinnu láti dá ìhùwàsí yìí dúró. O lè gbà àkókó, ìfaradà, afíyèsí, àti òkun láti dẹkùn àwọn òrò òdì tí a sọ sí ara wa pátápátá nítorí fún òpò lára wa o tí di bára kú, O tí férèé dí àdánidá Kejì wón. Níwòn ìgbà to bá tí mò ohun to ń se, lóyè pé o ma ní láti ṣèdíwọ́ ará rè àti àwon èrò to dúró it lápapò. Mímò ìhùwàsí yìí ni kòkòrò láti dẹkùn.

Nígbà tí a bá ń darí àwọn èrò àti àwọn òrò wa, a gbà ayé wa padà! Mo pè o níjà lónìí láti sọ sí ARA RÈ…àwọn òrò láti gbé to live by. ìsè yìí se ìgbésẹ tó ṣe pàtàkì ní mímú àwọn èrò rè sábè ìdarí àti léyìn àwọn òrò wa. Àsìkò tí tó ṣe m sísọ agbára àti òtító sínú ayé wa nípa kiko àwọn gbólóhùn īfàsesí òjòójumo.

Àkókó, bèrè pèlú èyíkéyìí èrò búburú tàbí òrò búburú tí o ń sò si ara rè tó ṣàkóso tàbí àyotúnyo tàbí èrò rè. Kò èyíkéyìí iró tí o ń gbàgbó. Òrò búburú wo ní o wò è lórùn àti ṣèdíwọ́ fún o láti gbé ìgbé ayé rè tó dára jù li? Tí àwọn èrò wa, òrò tí a ń sò sí ara wa tàbí òrò tí kò pápò mò o òtító Olórun, a ní láti dá won mò.

Èkejì, wa àwọn Ìwé Mímó gégé oògùn láti yanjú fún àwọn èrò búburú tàbí àwọn ìrò. Àwọn òtító èmí yìí lè tú o sílè lówó àwọn ìrò yìí àti agbára odi/ àpẹẹrẹ. De àwọn èrò àti àwọn òrò ní sí àwọn òtító Rè! Yàn àwọn òrò tó pápò mò pèlú Òrò Olórun

Paríparí, kékòó àwọn Ìwé Mímó àti se àwọn gbólóhùn òrò tó dára, ìbámu pèlú wón tí o lè gbà àti sò pàdà sí ayé rè. Àwọn èyí jẹ́ gbólóhùn tó dára tó pápò mo ÒTÍTÓ. Se àkọsílẹ̀ rè. Gbólóhùn wo ní tí o lè sò tó máa mú ògo fún Ọlórun àti àbájáde tó tún dára sínú ayé rè?

Sísọ àwọn gbólóhùn yìí lójòójumo máa ràn é lówó tó bèrè sí ṣàkóso ayé rè nípa sisàkóso ahón e. Kö láti sọ ohunkóhun yàtò sí Òrò Ọlọ́run nípa ayé è àti ipò rè. Gbà àṣẹ lóri ayé rè pèlú àwon Ìwé Mímó àti agbára òrò enú re àwọn òrò rè tí o ń sò. Àwọn èyí ní Àwọn ÒRÒ TÍ GBÉ.

Ronú:

Kíni àwọn èrò àti àwọn ìrò tí ń lọ lórí rè tí kò bá Òrò Olórun mú m? Ronú láti yan àwọn òtító tó ní fúnni níyè láti rọpo àwọn èrò yen.

Ádùrá:

Olúwa, Mo fé sò ìyè àti gbé láti òtító Yín nípa mi l. Lópò ìgbà, Mo nímólárá pé o kó sínú òfin búburú àti ẹrú wíwó ayé léjìká mi. É ràn mí lówó láti wà òtítọ Yín tó ń fúnni níyè àti sàsàrò lórí wón lójoojúmó.

Day 4Day 6

Nípa Ìpèsè yìí

Speaking Life

Ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀, àwọn ọ̀rọ̀ tó kún fọ́fọ́ fún agbára! Àwọn ọ̀rọ̀ tí ń múni ró tàbí èyí tí ń fani lulẹ̀. Àwọn ọ̀rọ̀ tí ń fúnni ní ìyè tàbí èyí tí ń mú ikú wá. Èyí tí o yàn wá kù sí ọ lọ́wọ́. Ẹ jẹ́ ká jọ ṣe àgbéyẹ̀wò agbára inú àwọn ọ̀rọ̀ tó ń tẹnu wa jáde.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Roxane Parks fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, Jọ̀wọ́ lọ sí: http://www.roxanneparks.com/home.html