Irin-ìdáàbòbò: Yíyẹra fún Àbámọ̀ ní Ìgbésí-ayé RẹÀpẹrẹ

Guardrails: Avoiding Regrets In Your Life

Ọjọ́ 2 nínú 5

Àwọn abamọ tí o dun wa jù má sábà nise pẹlu àwọn tí a kà sí ọrẹ. Bóyá abamọ tirẹ niiṣe pẹlu alabaṣepọ, ọrẹ, tàbí orekunrin atijọ. Bóyá àwọn ọrẹ tí o ro pé ko bá dára kí o ma padee won rara. Kódà bí o bá dá wà, o fẹ rẹ̀ jẹ́ wípé abamọ tí o dun ọ jù wá láti ipasẹ Ibaṣepọ pẹ̀lú ẹlòmíràn.

Àwọn Ibaṣepọ tí a kabamo yìí kọ wa (ní ọna tí ole) wípé ọjọ iwájúu wa niise pẹlu àwọn tí a n lo àkókò wa pẹ̀lú. Ìdí niyi tí a se nilo itosona nípa Ibaṣepọ.

Solomoni, ọ̀kan nínú àwọn tí o gbọn jùlọ l'ayé, kọ wípé "Bá àwọn ọlọgbọn rìn, iwọ yíò sì gbón..." O tumọ ṣí wípé ọgbọn a máa ràn mo ènìyàn. Gbé ìgbésí ayé pẹlu ọlọgbọn, tó bá yá, iwọ náà yíò gbọn, béè ní máa ṣẹlẹ̀.

Ida Kejì rẹ ni pé, "... ẹnití o bá ṣọrẹ òmùgò, ibi yíò baa." Tí o bá n bá òmùgò rìn, iwọ yíò b'awọn pin nínú iya tí o ba jeyo nípa ìpinu tí wọ́n bá se. Ṣé o ye ọ. Ohun tí o bá ṣẹlẹ̀ ṣíi ní yíò ṣẹlẹ̀ sí iwọ náà, ojú tí wọ́n fi n wo, ni wọn o fi wo iwọ náà.

Ìdáàbòbò nípa Ibaṣepọ ràn wá lọwọ kí a má ba kó sí ìwà òmùgò. Nitorinaa tí o bá ti n ro nípa ọrẹ nínú, gbé àwọn ìdáàbòbò mẹta yìí yẹwo. Tí òkan nínú àwọn ohun yìí bá ṣẹlẹ̀, jẹ kí ọ ṣí iyè rẹ kí ọ ma baa kabamo.

1. O ka ara rẹ mọ́ bí o ṣe nṣe gégé bíi ẹlòmíràn, o kò se bi ara rẹ mọ́.

2. O n gbero láti se nnkan tí kìí ṣe àdánwò sí ọ tẹlẹ

3. O n ro wípé kí àwon tí o féràn má mọ ibi tí o wa .

Rántí wípé, ìdáàbòbò kìí ṣe ohun kan tàbí enìkan ní dáradára tàbí aidara. Wọn tó ọ sọ́nà padà sí ọgbọn. Njẹ́ Ibaṣepọ rẹ kankan n ti o lo sínú ewu? Ìdáàbòbò èwo ni o n se aigbọran sí, àti pé kíni o fẹ se nípa rẹ̀

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Guardrails: Avoiding Regrets In Your Life

A máa fi irin í dáàbò ojú pópó síbè fún ààbò ọkọ̀ kí wọn má bàa yapa sì ibi tí ó lewu tàbí ibi tí kò yẹ kí wọn rìn sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni a kì í rí wọn títí ao fi nílò wọn - nígbà náà, a ó ṣọpé pe wọn wa níbè. Báwo ni ìbá tí rí bí a bá ní iru irin í dáàbò bayi ninu àjọṣe wá, ìdọ́kòwò wá, àti isé wá? Báwo ni wọn yóò rí? Kí ni wọn ṣe lè pá wá mọ kúrò lọ́wọ́ ìkábàmọ̀? Fún ìwọ̀n ojo márùn-ún láti òní, ẹ jẹ ki a gbe bí a ṣe lè fi irú irin í dáàbò bayi sì ayé wa yẹ̀ wò.

More

A fé dúpé lówó North Point Ministries àti Andy Stanley fun ipèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò sí: https://www.anthology.study/anthology-app