O. Daf 109:21-22

O. Daf 109:21-22 YBCV

Ṣugbọn iwọ ṣe fun mi, Ọlọrun Oluwa, nitori orukọ rẹ: nitoriti ãnu rẹ dara, iwọ gbà mi. Nitoripe talaka ati olupọnju li emi aiya mi si gbọgbẹ ninu mi.