ORIN DAFIDI 109:21-22

ORIN DAFIDI 109:21-22 YCE

Ṣugbọn, ìwọ OLUWA Ọlọrun mi, gbèjà mi nítorí orúkọ rẹ, gbà mí! Nítorí ìfẹ́ rere rẹ tí kì í yẹ̀. Nítorí pé talaka ati aláìní ni mí, ọkàn mí bàjẹ́ lọpọlọpọ.