O. Daf 109:21-22
O. Daf 109:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ ṣe fún mi OLúWA Olódùmarè, ṣe rere fún mi nítorí orúkọ rẹ Nítorí tí àánú rẹ dára, ìwọ gbà mí Nítorí pé tálákà àti aláìní ni mí, àyà mi sì gbọgbẹ́ nínú mi.