Saamu 109:21-22

Saamu 109:21-22 YCB

Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ ṣe fún mi OLúWA Olódùmarè, ṣe rere fún mi nítorí orúkọ rẹ Nítorí tí àánú rẹ dára, ìwọ gbà mí Nítorí pé tálákà àti aláìní ni mí, àyà mi sì gbọgbẹ́ nínú mi.