ORIN DAFIDI 117:1-2

ORIN DAFIDI 117:1-2 YCE

Ẹ máa yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè! Ẹ yìn ín gbogbo ẹ̀yin eniyan, Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tóbi sí wa, òtítọ́ rẹ̀ sì wà títí laelae.