O. Daf 117:1-2
O. Daf 117:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ẹ yin OLúWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn. Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ OLúWA dúró láéláé.
O. Daf 117:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ ma yìn Oluwa, ẹnyin orilẹ-ède gbogbo: ẹ yìn i, ẹnyin enia gbogbo. Nitoriti iṣeun ãnu rẹ̀ pọ̀ si wa: ati otitọ Oluwa duro lailai. Ẹ yìn Oluwa!
O. Daf 117:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹ ma yìn Oluwa, ẹnyin orilẹ-ède gbogbo: ẹ yìn i, ẹnyin enia gbogbo. Nitoriti iṣeun ãnu rẹ̀ pọ̀ si wa: ati otitọ Oluwa duro lailai. Ẹ yìn Oluwa!