ORIN DAFIDI 117

117
Yíyin OLUWA
1Ẹ máa yin OLUWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè!
Ẹ yìn ín gbogbo ẹ̀yin eniyan,
2Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tóbi sí wa,
òtítọ́ rẹ̀ sì wà títí laelae.
Ẹ máa yin OLUWA.#Rom 15:11

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

ORIN DAFIDI 117: YCE

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa