O. Daf 117

117
Yíyin OLUWA
1Ẹ ma yìn Oluwa, ẹnyin orilẹ-ède gbogbo: ẹ yìn i, ẹnyin enia gbogbo.
2Nitoriti iṣeun ãnu rẹ̀ pọ̀ si wa: ati otitọ Oluwa duro lailai. Ẹ yìn Oluwa!

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

O. Daf 117: YBCV

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa