Ẹ yin OLúWA, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn. Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ OLúWA dúró láéláé.
Kà Saamu 117
Feti si Saamu 117
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 117:1-2
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò