Ààyè Ìsinmi Àpẹrẹ

Breathing Room

Ọjọ́ 2 nínú 5

p > Ó kò ní láti jẹ ẹlẹ́sin lati mọ̀ nípa tabi làti yà ọjọ́ tí a fí ńsimi sọ́tọ̀— tí a pè ní ọjọ ìsinmi. Gbogbo wa ní ó gbádùn bí ìparí ọ̀sẹ̀ ṣe ń wọlé wẹ́rẹ́, bóyá tí a sì ń fi ojú sọ́nà láti sún, kí á sinmi níbi iṣẹ ṣíṣe. Ṣugbọn ti o ba kàn rò pé ọjọ isimi
bí ọjọ́ isimi ti o dakẹ rọ́rọ́, ìwọ tí sọ apá kan rẹ ti o dára julọ nù — apá kan ti yíò fun ọ ni ààyè ìsinmi níkẹyìn.

< p > Jẹ ki a ṣe àfiyèsí diẹ ninu itan ti o yori si awọn ọrọ oni lati inú ìwé Eksodu nibiti Ọlọrun ti fí ọjọ isimi lọ́lẹ̀. Awọn eniyan Israeli jẹ ẹrú ni Egipti fun irínwó ọdún, ti n ṣiṣẹ ní ojojumo, ni gbogbo ọjọ. Nígbà náà wọn ni òmìnira, gbogbo orilẹ-ede naa n rín kiri ni aginju fun ogójì ọdun diẹ si. Ati pe nibi ni Ọlọrun tí pàṣẹ fún wọn lati ṣe akiyesi ọjọ isimi — lati yà ọjọ kan sí ọ̀tọ̀ ni ọsẹ kọọkan.

< p > < Ọlọrun sọ fún àkójopọ̀ awọn eniyan ti wọn ti n ṣiṣẹ yíká àágo fun ọ̀pọ̀ ọgọrun ọdun ati awọn ti o ń gbiyanju bayi lati wa ounjẹ tí ó to lati bọ́ ẹgbẹẹgbẹrun eniyan ni agbedemeji aginju kan ti wọn ní láti yà ọjọ́ kan sọ́tọ̀ < / em > O gbọdọ jẹ ohun tó burú! Ti wọn ko ba ṣiṣẹ ni ọjọ yẹn, wọn ko ní jẹun ní ọjọ yẹn. < / p > < p > Ọlọrun ti to nkankan bótilẹ̀jẹ́pé. Ni Eksodu 31:13, o ṣàlàyé pe pípa ọjọ isimi mọ yíò jẹ ami fun awọn ọmọ Israeli pe “ Emi ni Oluwa... ” Ọlọrun n sọ fun wọn ( ati àwa náà pẹ̀lú), < em > Mo fẹ lati fi han fun ọ pe mo jẹ́ ẹni tí a lè gbọ́ kan lè. Mo mọ pe o bẹru ebi pípa. Ṣugbọn emi yíò fihan, pe a le gbẹkẹle mi láti ọ̀sẹ̀ dé ọ̀sẹ̀. < / em > < / p > p < Bóyá ó mọ ìyókù itan náà. Pẹlu manna ati ẹiyẹ àparò, Ọlọrun fí idahun si ìbẹ̀rù wọn lórí ebi pípa nípa fífi òtítọ́ pese akara ojoojumọ fún wọn, paapaa ni ọjọ ti o yà sọ́tọ̀ fún wọn lati sinmi tí ko sí iṣẹ́ kankan.

< p > Aṣẹ Ọlọrun fún wa láti sinmi jẹ ìpè fún wa lati gbẹ́kẹ̀le. Nigba ti a ba bẹru láti jẹ ìpè naa yíò ṣe ipalara ìmọ̀lára awọn ọrẹ wa, a le gbekele Ọlọrun lati daabobo ìbásepọ̀ láàárín ọrẹ yẹn. Nígbàtí a ba bẹ̀rù pe ile wa kere pupọ, ọkọ ayọkẹlẹ wa ti dagba ju, tabi awọn aṣọ wa ti ṣá, a le gbẹ́kẹ̀le Ọlọrun pe iye wa ko ni fi ṣe pẹ̀lú awọn ohun elo wọnyẹn. Ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọrun dipo eyín jíjẹ àti ìkọjá àyè wá ní àkótán ọ̀nà ààyè ìsinmi àìlópin. < / p >

Idagbasoke

 

Bọtini: ọjọ_2

ọjọ_2
Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Breathing Room

Ǹjẹ́ ó máa ń rí lára ni ìgbàkígbà wipé ó kò gbádùn ohunkóhun nítorí ó ñ gbìyànjú láti se gbogbo ohun? Ó nse opọ̀ nǹkan lẹ́ẹ̀kan nipase ònà rè ni ayé pèlú àwon ololufe rè. . .Ó jafafa. Sùgbọ́n ó n sàárẹ̀. Ó kan ní-lò àyè èémi die. Pèlú ipèwá sókí onìyàlénu kan, Olórun pèsè ònà láti ropo ìyára rè to dùn kọjá ààlà fun èyí to ma mu àlàáfíà wa ni ìkẹyìn. Ètò yìí ma fi báwo hàn é.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ North Point Ministries àti Sandra Stanley fun ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò sí: http://breathingroom.org