Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 1 nínú 91

Adventi jé àkókò ọsẹ mẹrin ti ìrètí ìdúró yíká gbogbo ayé. O jẹ́ àkókò tí a n múra ọkàn wa silẹ láti rí Olùgbàlà a wa, Mesaya tí a ti sọ tẹlẹ. O jẹ́ àkókò otito àti fún kíkọ́ àwọn ọmọ wa nípa ìbí Jésù láti ipasẹ wúndíá, ìgbé ayé, iku àti àjínde. Kí àkókò yi fa ọkàn wa padà síi òtítọ nípa ohun tí a ti ṣe àti tunbo sún wa sí ọdún titun ti o kún fún ìrètí àti imurasilẹ fún ifarahan ologo ti o nbọ

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Sàlàyé adventi fún ìdílé è rẹ, ki o sí gbero fún àkókò yí lojojumo. Sami medogbon sára abela gígùn. Kọ nọmba ookan sí medogbon sí lára, ki awọn nọmba tẹle ara wọn. Tan abela yí, ní gbogbo irọlẹ bí o ṣe nsi ọrọ Ọlọrun ní ikọkọ tabi pẹlu gbogbo ìdílé, jẹ kí abela náà jó nọmba kan ní ale kan.

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu Ọlọrun pẹ̀lú ẹda àti ènìyàn.
Jenesisi 1:27-28, 2:16-17 ati Jeremaya 33:19-22

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Olorun npa ìlérí majẹmu mọ ní gbogbo ìgbà. Ọrọ rẹ dájú. Njẹ iwọ gbẹkẹle? Fetí sílẹ̀ ṣí àwọn ọrọ rẹ. Ṣe iwọ n pa ìlérí tí o ba se mọ? Ṣe o nsọ ohun tí ọ wá lọkàn rẹ, ṣe o nṣe ohun tí o sọ?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Gbogbo àwọn ẹda ti Ọlọrun àti Ọba wa"
Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org