Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 2 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Ṣé ọ ṣe àkíyèsí ọrọ rẹ? Ṣé o dá ọ lójú?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Asọtẹlẹ kini nípa Mesaya tí ọ nbọ
Jenesisi 3:1-15

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Jésù àti satani yóò jagun. Tani yíò ṣẹgun? Ọmọ ti Obìnrin na farapa, ṣùgbọ́n a tẹ satani mole. Báwo ni Jésù ṣe borí satani nínú ayé è rẹ? Báwo ni ayé è rẹ ṣe n fi idupe hàn sí Jésù?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Wá, wá Immanuẹli"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org