Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 6 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Báwo ni ọ ṣe gbàgbọ́ ti ọ sí se ìgbọràn sí Ọlọ́run lana?

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Majẹmu pẹ̀lú Abrahamu wá pẹ̀lú ìlérí àwọn Ọba
Jenesisi 17:1-8

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ọlọ́run sọ wípé àwọn ọba yíò tí ipasẹ̀ Abrahamu wa. Njẹ́ iwọ lè dárúkọ èyíkéyìí nínú àwọn ọba Israẹli? Njẹ́ iwọ mọ ẹnití a npè tí Oba àwọn ọba?
Ṣé ọ ti jọwọ ayé rẹ si Ọba Jésù?

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, kí ọ sì dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Awọn angẹli kọrin"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 5Ọjọ́ 7

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org