Dide: Kristi un Bọ!Àpẹrẹ

Advent: Christ Is Coming!

Ọjọ́ 8 nínú 91

TAN IMỌLẸ NÁÀ

A n'reti Mesaya!
Njẹ iwọ gbé pẹlú ìlànà Orin Dáfídì 105:1 lanan

KA AWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ
Àwọn ènìyàn Ọlọrun: Àwọn ènìyàn mimọ ti wọn níye lórí, ìjọba àwọn àlùfáà.
Eksodu 19:1-6

DAHUN PẸLU ÌJỌSÌN

Ṣe ìjọsìn pẹlu ayé rẹ
Ati gbà ọ là àti wípé iwọ níye lórí. Sọ nípa ohun kàn tí iwọ ka sì ohun tí o níye lórí. Ṣé iwọ fẹ́
dáàbò bo, kí o sí tọjú rẹ lónà pàtàkì? Bẹẹ gẹ́gẹ́ ni Ọlọrun nṣe pẹlú rẹ

Ṣe ìjọsìn pẹlu adura
Lo ẹsẹ Bíbélì lati júbà, jewo, yin, ati dupẹ lọwọ Ọlọrun.

Ṣe ìjọsìn pẹlu orin
Kọ orin "Alé ipalọlọ"

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 7Ọjọ́ 9

Nípa Ìpèsè yìí

Advent: Christ Is Coming!

Èkó kíkà Adventi yìí láti ọwọ iranse Thistlebend wà fún àwọn ìdílé tàbí ẹnikọọkan láti pèsè ọkàn wa fún ijoyo ọ ti Mesaya. O sọ nípa pàtàkì ohun tí wíwá Kristi jẹ́ fún ayée wa l'oni. Ase e kí a lè bẹrẹ rẹ ní December 1. A gbà l'adura pé kí o jẹ́ ohun ìrántí pipẹ fún ìdílé rẹ láti lo itosona yi láti rí ìdúróṣinṣin Bàbáa rẹ, ìfẹ́ Majẹmu fún ẹnikọọkan yin.

More

A fẹ lati dúpẹ lọwọ ilese Thistlebend fun kiko eto yii. Fun alaye sii, jọwọ lọsi: www.thistlebendministries.org