Ohun Gbogbo Dọ̀tunÀpẹrẹ

All Things New

Ọjọ́ 5 nínú 5

Ràntí pé Póòlù sàlàyé fún àwon Kọ́ríńtì pé sísún ìrín ajò rè síwájú wá láti ọkàn-àyà tòótọ́.

Òtítọ́ inú lónà kan sáá jé àwọn ànímọ́ tó dára tó sonù ní àkókò wa, tó kún fún ètàn,tó se ìbòòji fún òtító,àwon ìdáhùnpadà àìjapanta-oníjàgídíjàgan, iró pípa, àti òrò dídùn lásán.Báwo ni ara Kristi o bá se túbọ lọ́ràá sii tí a bá jé mímógaara àti olóòótọ́ ọkàn sí ara yín lẹ́nìkìíní-kejì pèlú sí àwon tó wà ní ayé bákan náà?

A lè máà mọ̀ọ́mọ̀ so fún àwon èèyàn pé bẹ́ẹ̀ni nígbà tí a fé so béèkó, tàbí bẹ́ẹ̀kọ́ nígbà tí a fé so bẹ́ẹ̀ni, àmó a túbò se lọ́nà àrékérekè.

Tí a bá dúró nibi a máà tí ní ẹ̀kọ́ tó ñ ran ní lọ́wọ́ ní ìsòtító àti aláìfọ̀rọ̀bọpobọyọ̀. Àmó Póòlù ní díè síi fún wa jù riru mítà ìsòtító wa sókè lo.

Ìyàtò kan tí ìgbàgbọ́ Kristẹni kì i se nípa àseyorí nínú ìlànà ìwà rere sáà tàbí láti dà bí Kristeni ọmọlúwàbí nítorí láti jé ènì tó dára gan-an. Póòlù tíe tí lo òpò ayé rè ní ìlépa yen, ṣàṣeyọrí oníráwo nínú èkó Júù, jijẹ́ ọ̀kan lára ọmọ-ẹgbẹ́ àwọn Farisí, tí a kó nípasè rábì jàǹkàn-jàǹkàn, àti jé olódodo lójú ara ẹni lónà pípé. Sùgbón o rí i pé gbogbo “dáradára” rè já mọ́ nǹkan bí òkìtì ẹlẹ́bọ́tọ (Fílípí. 3:8).

Nísinsìnyí tí o gbẹjọ́ àwon ìwà rè rò sí àwon Kọ́ríńtì, kókó òrò rè ní pé láti ṣiyè méjì sí won yóò lòdì sí òkan lára ìpìlè ìgbàgbọ́ rè: Olórun jé olùsòtító. Kò lè paró. Kò lè padà lóri òrò Rè. Ó sélérí májẹ̀mú láti rà àwon omo Rè padà, àti gbogbo ìlérí títí kan “béèni” ní inú Jésù. Àtipe Jésù ní béèni Olórun sí wa fún ìgbè ayé tó nítumò àti onírétí tí a ha ń nàgà fun (2 Kọ́ríńtì. 1:19-20). Lónà mìràn, “Ní ìsopò sí [Jésù], ọ̀kọ̀ọ̀kan lára ìlérí Olórun gbà ‘béèni’ fún ìdáhùn.” Tí Olórun kò bá dúró sójú kan pèlú àwon béèni àti àwon béèkó Rè, o dára, nígbà náà kì i see Póòlù.

Bóyá òkan lára ìdí tí a kò jé olóòótọ́ ọkàn nígbogbo ìgbà tàbí aláìfọ̀rọ̀bọpobọyọ̀ nínú ìbásepò ní nítorí a kò wà déédédé nínú “béèni” tí Kristi. Mo tí mò kéèkì rírọ̀, àtipe nígbà mìràn dà ríborìbo, àwon ipò ríborìbo nítorí mo fé mú ayé mi sisé bí mo tí fé kí o se. Fífara mó béèni tàbí béèkó lè halè mó ìlépa náà. Àmó nígbà tí mo bá lè, èèyàn Rè àti àkóso lórí ayé mi, mi o ní láti dà ríborìbo tàbí àgàbàgèbe.

Bí a ti ń ti parí èkó wa, kí ni o jé apá tí ó dájú jù lo fún o?

Ìwé mímọ́

Day 4

Nípa Ìpèsè yìí

All Things New

Ní ìrìn ajó lo sí Ìwé Kọ́ríńtì, Gbogbo ohun jé tuntun sàyèwò ẹ̀kọ́ ìsìn Póòlù tí ìgbàgbọ́ onígboyà ní ayé yìí tí Olórun pé wa láti nígboyà. Kelly Minter ràn wá lọ́wọ́ láti lóye pé ìrìn Kristeni dá bíi pé o yàtò sí ìtèsí àdánidá, àmó fí hàn dájú pé o dára jú ayérayé àti àìlópin. Ní ètò kíkà olójó márùn-ún, yóò sàyèwò àwon awuyewuye bí: bí won se yanjù àwon ìbasépò tó sòro, gbigbéklè Olórun, pèlú orúko rere rè, mimú ìdúró ìdánimọ̀ rè nínú Kristi, lilóye ète ìjìyà àti ìpèsè Olórun nínú è, àti báwo ní a se lè jé ìmọ́lẹ̀ ìhìnrere nínú ayé.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ àwon obìnrin LifeWay fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé die síi, jọ̀wọ́ lọ sí http://www.lifeway.com/allthingsnew