Ohun Gbogbo Dọ̀tunÀpẹrẹ
![All Things New](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F4872%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Nígbà tí Póòlù sòrò nípa àwon ìjìyà Kristi tó kún àkúnwòsílè sínú ayé wa, o lè túmò sí àwon èrò tó wonú ara won: 1. Àwon ìjìyà lórí àkosílè Kristi. 2. Àwon ìjìyà tí a yàn fún wa látówó Kristi. 3. Àwon ìjìyà tó wa ní àjose pèlú Kristi. 4. Àwon ìjìyà tí Kristi faradà.[1] Ohun tí mo gbàgbó pé o sé pàtàkì fún wa láti mò pé gégé bí onígbàgbó, a máa ní ìpalára àwọn nǹkan kan tó yàtọ̀ pátápátá sí àjose wa nínú Krisi ìyà. Many Òpò Kristeni ñ jé ìyà inúnibíni gidi gan káàkiri ayé nígbà tí àwọn mìíràn ǹ kojú ìrora tó kéré, àmó tún jé onírora, ònà fún ìgbàgbó won. Póòlù rí i pé ìbákẹ́gbẹ́pọ̀ kan wa tó ń wáyé pèlú Jésù ní àwon àkòkó ìjìyà nítorí kò sí ènì tô mò ìjìyà jù Òun lo.
Mi kò tíì pàdé ènìkan tó gbádùn ìjìya, àmó mo tí pàdé ènì tó tí rí àjose tímótímó pèlú Kristi pèlú Jésù àárín ìjìyà won. Àwon apá Jésù kan wà tí o kò lè mò ní ipá ònà ìròrùn, àtipe, gbárá tí o bá tí tó sisùmo pèlú Rè wò o kò ní dòwò rè fún ipa ọ̀nà tó jọ̀lọ̀. Ní àfikún sí ìrírí àjose àkànse pèlú (Fíllípi. 3:10), Póòlù se ìfihàn ìdí mìíràn tí ìjìyà mú ìbúkún wá.
Ìgbàkígbà tí ìjìyà Jésù bá kún àkúnwósílè sínú ayé wa ohun tó kún àkúnwòsílè jáde nínú wa ní ìtúnú Olórun (2 Kọ́ríńtì. 1:5). Èyí jé is ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀!
Òkan lára ìkéde tó rewà jù nínú Ìwé Mímó ní a rí ní esè 4, “O tù wá nínú ní nínú gbogbo ìpọ́njú wa, kí a bá lè tù àwon elòmíràn nínú tó wà nínú èyíkéyìí ìpónjú” (HCSB). Nígbà tí a bá lọ jákèjádò ìsòro, o sábà má ñ sòro láti wò kója ìrora wa. Àmó nígbà tí a bá rí ète ñla nínú ìjìyà wa ṣàrà ọ̀tọ̀ nígbà tí a bá rí i àwon ìrírí má dúró gégé bí ìtúnú tó sàrà òtò sí àwon elòmíràn àwon tó ñ la irú àdánwo náà kojá.
Ìjìyà Kristi àti ìtùnú Rè jo sáré ní ayé wa, ìfẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́. Gégé bí Kristeni, a kò lè ní láti jìyà láìsí ìtùnú Kristi, àtipe mo gbàgbó pé àwon ìtùnú kan wà tí a kò lè mò láìsí ìjìyà Rè. Tí o ñ bá la àdánwò kojá, bóyá oòkan tí a kò lè faradà tí kò lágbára láti faradà, fà láti ìtùnú Olórun tó lo láti ènì Jésù sínú ayé rè.O sélérí ní dídíwòn ìrora rè. Nígbà tí o bá pàdé pèlú ìtùnú Olórun, ìwo yóò ní ìháragàgà láti dé ojú ogbé èlómíràn tó wà ní irú ìrora kán nítorí ìtùnú Olórun ñ kún àkúnya ní àbúda. Ìwo wàá ní tó pò repete tó láti pìn.
[1] David E. Garland, The New American Commentary, Volume 29, 2 Corinthians (Nashville: Broadman & Holman Publishers, 1999) accessed on August 7, 2017 via mywsb.com.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
![All Things New](/_next/image?url=https%3A%2F%2Fimageproxy.youversionapi.com%2Fhttps%3A%2F%2Fs3.amazonaws.com%2Fyvplans%2F4872%2F1280x720.jpg&w=3840&q=75)
Ní ìrìn ajó lo sí Ìwé Kọ́ríńtì, Gbogbo ohun jé tuntun sàyèwò ẹ̀kọ́ ìsìn Póòlù tí ìgbàgbọ́ onígboyà ní ayé yìí tí Olórun pé wa láti nígboyà. Kelly Minter ràn wá lọ́wọ́ láti lóye pé ìrìn Kristeni dá bíi pé o yàtò sí ìtèsí àdánidá, àmó fí hàn dájú pé o dára jú ayérayé àti àìlópin. Ní ètò kíkà olójó márùn-ún, yóò sàyèwò àwon awuyewuye bí: bí won se yanjù àwon ìbasépò tó sòro, gbigbéklè Olórun, pèlú orúko rere rè, mimú ìdúró ìdánimọ̀ rè nínú Kristi, lilóye ète ìjìyà àti ìpèsè Olórun nínú è, àti báwo ní a se lè jé ìmọ́lẹ̀ ìhìnrere nínú ayé.
More