Ìgbẹ́kẹ̀lé, Isé àsekára, Ati ÌsimiÀpẹrẹ

Trust, Hustle, And Rest

Ọjọ́ 2 nínú 4

Agbẹkẹle

Nínú gbogbo ìwé mímọ̀, a sọ fún wa wípé Ọlọ́run nií máa fún wa ní àbájáde nípasẹ iṣẹ́ wa, kìí ṣe àwa. Ìwé Kronika kínní 29:12 sọ wípé "Láti ọdọ rẹ wà ni ọrọ̀ àti ọlá ti n wa, o si n joba lórí ohun gbogbo." Diutaronomi 8:17-18 ka báyìí wípé, "E ṣọra, kí e ma baa sọ nínú ọkàn yín pé agbára yín, àti ipá yín ni o mu ọrọ yìí wá fun yín." E rántí Oa Ọlọ́run yín nítorí òun ni o fun yín ní agbára láti di ọlọrọ."

Ìwé gbajúmọ̀ kan sọ wípé, ní lúwa gbogbo ènìyàn le ṣe ifilole ìṣòwò laseyori, tàbí kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ adaro tí o gbajumo lórí ẹ̀rọ ayélujára, o le jẹ́ kí a máa ro wípé iṣẹ́ àṣẹ kara wa ni o n fún wa ní àwọn àbájáde nípasẹ̀ ipá wa. Bí a o ṣe rí nínú ètò ti ọla, Ọlọrun pàṣẹ wípé kí a ṣe iṣẹ́ asekara o si n lo iṣẹ́ asekara wa láti pèsè àbájáde nípasẹ wa. Sùgbón nígbàtí a bá bẹrẹ èyíkéyìí iṣẹ́ titun, a gbọdọ̀ bẹrẹ nípa rírí iṣẹ́ yìí pé àbájáde rẹ wá láti ọdọ Ọlọrun

Nínú Ìwé Òwe 16, Solomoni bẹrẹ ní ṣíṣe ntẹlee, agbẹkẹle, iṣẹ́ asekara, àti ìsinmi tí o yẹ kí o sami si èyíkéyìí ipa tí àwa Kristiani n lépa. Ní ẹsẹ kẹta orí Bíbélì yìí, ọkùnrin tí o gbonju laye pàṣẹ wípé, "Fi gbogbo adawole rẹ lé Olúwa l'ọwọ, ẹrọ ọkàn rẹ yóò sì yọrí sí rere." Nitorinaa kí a tó bẹrẹ iṣẹ́ asekara, a ní láti fi gbogbo adawole wa le Ollúwal'ọwọ. Báwo ni o ṣe rí ní imusẹ?

Fun àwọn tí o ṣẹṣẹ bẹrẹ, o rí bíi kí a pa àwọn ẹsẹ Bíbélì tí a ti kà loni mọ nínú ọkàn wa, kí wọn lè máa rán wa létí wípé Olúlúwai o n se àbájáde esi iṣẹ́ wa, kìí ṣe àwa. Léèkejì, kí a fi gbogbo idlúwawalé Ollúwúwaọwọ tí a bá ti too lo nínú adura, kí a sì sọ fún nípa igbẹkẹle wa nínú rẹ̀. Lakotan, pẹ̀lú sísọ nípa igbẹkẹle wa fùn Ọlọrun, o ṣe pàtàklúwaaọ nípa igbẹkẹle yí fún àwọn tí o wa layika wa. Ní ayé tí o ni àṣà a "kí a máa lo ipá tiwa láti se ohunkóhun," a o ya àwa Kristiani soto nínú ayé tí a bá ti ríi wípé Olúlúwawao n fún wa ní àbájáde esi nípasẹ iṣẹ́ e wa, kìí ṣllúwa

Sùgbón bí a o se ríi ní ọla, igbẹkẹle jẹ ọkan nínú ohun tí oye kí a se. Oye kí a ṣe iṣẹ́ kara ninu ise wa tí a bá fẹ jẹ irinṣẹ tí o munadoko ní ọwọ ẹni tí o pe wá.

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Trust, Hustle, And Rest

Bíbélì pàṣẹ fún wa pé kí a ṣiṣẹ́ karakara, ṣugbọn o tun so fún wa wípé Ọlọrun níí má se àbájáde iṣẹ wa, kìí se àwa. Bí ètò ọlọjọ mérin yìí yíò ṣe fi hàn wá, Kristiani tí o ba n sise gbọdọ gba ibaṣepọ tí o wa nínú kí a gbẹkẹle àti kí a ṣiṣẹ́ karakara láti le rí Ìsinmi tí ọjọ ìsinmi tootọ.

More

A fé láti dúpe lówó Jordan Raynor fún ìpèsè ètò yìí. Fún alaye die sí, Jowo lo si: http://www.jordanraynor.com/trust/