Dìde sí Ẹ̀rù RẹÀpẹrẹ

Don't Settle For Safe

Ọjọ́ 3 nínú 3

Gbé nínu òtító ẹni tí o jẹ́

Gbogbo ohun tí ó nílò láti jé eni tí ó rẹwà, ṣe àṣeyọrí, ṣe oun alára gbàyídá, jẹ́ alábùkún fún, ṣe fọkàn tán, ṣe bọ̀wọ̀ fún, bu ọlá fu ati láti máa dun nú tí wà nínú ayé rèé tẹ́lẹ̀ tẹ́lẹ̀. Ó lè jẹ́ wípé kò rí bẹ́ẹ̀, àmọ́ nítorí pé òhún fojú sí àwọn nǹkan tí kò yẹ. Gbogbo ohun tí o bá bí laáyì tó àkókò rẹ̀ fi ààyè sílè fún oríṣiríṣi ìṣòro. Àwọn oríṣiríṣi ìṣòro tí òhún dojú kọ èyí tí ó mú kí o máa ní ìgbàgbọ́ jẹ́ àwọn nǹkan tí o tètè gbé jáde laáyì pé ọjọ́. Síbẹ̀, Ọlọ́run ní ojú réré tí ó pọ̀ tó bẹ tí Ó fi kọ́ ọ ní ẹ̀kọ́ nínú ìrìn àjò náà èyí tí ó mú ọ di ènìyàn pàtàkì fún lílo rẹ̀.

Má ṣe ṣe àkóso ayé rẹ fún raara rẹ. Darí ọkàn rẹ tí ó gbàgbó pé o mọn ṣe jùlọ. Gbàgbó wípé tí òo bá ní nǹkan á jẹ́ wípé o kò tí ṣe tàn fún ni. Gbàgbó wípé tí ó bá wà lórí abọ́ rẹ, a jẹ́ wípé o ní agbára láti lè ṣeé. Fi òpin sí láti ma ní iyè méjì lóri ipá rẹ àti ma dán ìgbàgbọ́ rẹ. Má se ṣe ohun tí o rò wípé ó tọ́; ṣe ohun tí ó ma sọ ọ́ di ènìyàn tí ó dára. Èyí leè gba wípé kí o ní ipele ọ́tun míràn nínu ìkó Ira ẹni ní ìjánu tàbí ipele tí ó jin lè nínu àti máa fi ai ní àbò rẹ hàn. Oríṣiríṣi nǹkan ni ó ma wà èyí tí ó leè fún ọ ní àyè láti sá fún àwọn nǹkan ìpè níja yìí. Má ṣe lò wọ́n. Kàkà bẹ́ẹ̀, rí àwọn àìpéníye rẹ gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe jẹ́: èyí tó jẹ́ àwọn ibi ààyè tí a le fi ìfẹ́ dí. Ní ìfẹ́ á rà re tó bẹẹ dé bi wípé àwọn nǹkan àìpéníye inú ààyè rẹ á rẹwà.

Lọ ní sùúrù. Tí o bá dé ibi òpin àjò tí ọkàn rẹ fẹ́, ó ri pé o ní ọ̀pọ̀ iṣẹ́ sí tún wà láti ṣe. Nígbà náà ni wà fẹ́ kí ọjọ́ máa tètè lọ kí o le gbádùn àyíká rẹ. Máa ṣe àwárí ohun tí ó rẹwà nínú ayé rẹ ló joo júmọ́. Ṣe àwò kọjá gbogbo gbèsè tí o fẹ́ san, ìjá ku lẹ́ rẹ, ìyá rẹ tí óun kú lọ, bàbá rẹ tí kò sí, ọmọ tó ti yẹ̀gàn, àti ìran tí kò wá sí imú ṣe. Wo ẹwà nínu ohun tí o ní láti rí ọjọ́ míràn àti ànfàní míràn. Má gbà mọn láti ma sin bí ìkan see rí. Yin Ọlọ́run fún wípé Àsìkò rẹ kò tí tó.

Ní ìgbà tí o bá bèèrè sí ní ṣe àwárí irú ẹni tí o jẹ́, àwọn ènìyàn á sì tún ma wò bóyá o sì tún ní ìwà tàti jọ́. Àwọn kan ma mú ìjá ku lè; àwọn míràn nínú wọn á ní ìtẹ́lọ́rùn láti kó nípa ènìyàn tuntun tí o jẹ́. Ṣe ètò ìsìn ìrántí fún àwọn tí ó bá fẹ́ di àṣìṣe àti ìpìnnu rẹ tí kò dára. Tó bá jẹ́ wípé àwọn nǹkan tí wọn gbà láti rí nìyẹn, nítorí náà wọn kò gbọdọ̀ ní àyè sí ìbùkún tí ó wà ní ìrìn àjò rẹ. Wọn kìí ṣe ènìyàn burúkú. Wọ́n jẹ́ ẹni tí ọkàn wọ́n tí bàjé. Àmọ́ o gbọdọ̀ gbà wọ́n láàyè láti báà ó lọ́kàn jẹ́. O gbọdọ̀ sọ irà rẹ nù nípa gbígbìn ìyànjú láti gbà wọ́n. Ní agbára tó tó láti yan ara rẹ.

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Don't Settle For Safe

Tí a kò bá dojú kọ àwọn ohùn àìbalẹ̀àyà, iyèméjì, àtiẹ̀rù, wọn á gbàkó so ayé rẹ. O kò leè pa àwọn ohùn yìí lẹ́nu mọ tàbí kí o dá'gunlá sí wọn. Nínú ètò ẹ̀kọ́ kíkà ọlọ́jọ́ mẹ́ta yìí, Sarah Jakes Roberts fi hàn bí a ṣe lè pè níjà àwọn àsémọ́ àtẹ̀yìnwá àti bí a ṣe ń kó mọ́ra àwọn ohun tí kò rọrùn kí á lè di ẹnití kò ṣeé dá duro.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Sarah Jakes Roberts àti Thomas Nelson tí wọ́n kọ ètò yí. Fún àlàyé síi, jọ̀wọ́ ṣe àbẹ̀wò sí: https://bit.ly/YV-DontSettleforSafe