Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ
Andy Stanley: Àwọn Ọ̀tá Ọkàn
Ìfọkànsìn Ojọ́ Kàrún
“Mímú Àwọn Ifè Ọkàn Rè Tó Ọlọ́run ”
Ìwé Mímọ́: Jákọ́bù 4:1-3
Ọ̀kọ̀ọ̀kan lára àwon ọ̀tá ọkàn wa máa ní agbára nípa èrò pé ẹnìkan je gbèsè nǹkan.Èbi so wípé, “mo jẹ e gbèsè.” a dáná ìbínú nípa èròngbà pé ó jẹ́ mi gbèsè. Ojúkòkòrò wá láàyè nípa ìléròpé pé mo jẹ ara mi gbèsè. Òràn ọkàn kẹrìn kò yàtò. Owú Òwu sọ wípé, “Ọlọ́run jẹ́ mi gbèsè.”
Nígbà tí a báa ronú nípa owú jíjẹ tàbí ìlara, léṣe kése a máa rò àwọn nǹkan tí àwọn ẹlòmíràn ní ti a wa se àìní —ìrísí, àwọn ìmònse, àwọn àǹfààní, ìlera, gíga, ogún, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lo. A lérò pé ìṣòro wá mbẹ pẹ̀lú ẹnì yẹn tó ní àwọn ohun tí a wà sáìnì. Àmọ́ ẹ jẹ kí a kojú e; Ọlọ́run lè tí tún gbogbo ìyẹn ṣe fún wa.Ohunkóhun tí o fún aládùúgbò e, Ọ́ lè tí fún ọ náà. Ìdí nìyẹn tí ó lè nérò pé Ó jẹ́ gbèsè.
Òwu lè pá ayé rè láyà àti pé má ń sọ́se ní àwọn ìbásẹ̀pò rè. Ìròyìn ayọ̀ nií pé, ohun ńlá yìí, bíi àwọn mẹ́ta yókù, ní ipò alágbára kan. Àti pé ó jẹ́ nkan tí ó kò lè rò: dẹ́kun ṣíṣe ojúkòkòrò sí ohun tí àwọn yòókù ní àti pé bẹ̀rẹ̀ sini béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run fún ohun Tí ó mọ̀ pé ohun tọ dára jù fún o
Gẹ́gẹ́ bí Jákọ́bù ṣe sò, rògbòdìyàn òde ara jẹ́ àbájáde rògbòdìyàn inú ara tọ́ tí ṣíṣe ọ̀nà rè sí oréfèé. A fẹ́ ohun kan àmọ́ a kò ní, nígbà náà a bẹ̀rẹ̀ sinijà pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn. Àwọn ifè okàn tí Jákọ́bù tọ́ka sí nínú ìwé ese Bíbélì je asojú fún òǹgbẹ—ipò òǹgbẹ fún àwọn ohun, owó, ìfẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́, àṣeyọrí, ìlọsíwájú, ìsúnmọ́ra tímọ́tímọ́, ìbálò, fàájì, àjọṣe, ìdòwò pọ̀.
Ní yín kí ni kí a ṣe pẹ̀lú àwọn ìfẹ́ ọkàn yìí àti àwọn ìdálọ́rùn tí a kò lè tẹ́lọ́rùn lẹ́kúnrẹ́rẹ́ àti pátápátá láé? Jákọ́bù sọ wípé kí a mú wọn sí Ẹnì tó kọ́kọ́ ṣe dá wón. Ká sọ lọ́nà mìíràn, Jákọ́bù ń fún wa ní ìgbaniláàyè láti sọ gbogbo ẹ̀dùn ọkàn ni ìjíròrò tí wọn ò sì sẹ́ àwọn ohun ẹlẹ́gbin inú wọn kúrò pẹ̀lú Olùṣẹ̀dá wa.
Gbogbo aájò tí ó ní, ńlá àti kékeré, ṣe pàtàkì sí Bàbá nítorí ìwọ ṣe pàtàkì sí Bàbá. Bóyá ó jẹ mọ́ ìfẹ́ ayé rè, isé ìgbésí ayé rè, ìgbéyàwó rè, àwọn òbí rè, àwọn ọmọ rẹ̀, rẹ ìnáwó rè, ẹ̀kọ́ rè,ìrísí rè, mú wá sọ́dọ̀ Rè. Àti pé máa mú wá sọ́dọ̀ Rè títí tí ó fi rí àlàáfíà láti dìde lọ́rúnkún àti kojú ọjọ́, ìdánilójú nínú ìmò pé Ó bìkítà fún ọ.
Jé kí ń fún ní ìdánilójú, ọkàn rè ṣé pàtàkì nígbà gbogbo sí ọkàn Rè.
Kí ní ohun tí kàn rè ro fún? Lọ àkókò láìṣe nnkan kan rárá, ṣe ìjíròrò tí a kò dilọ́wọ́ pẹ̀lú Ọlọ́run nípa ohun tó rò pé ó sáìnì. Béèrè lọ́wọ́ Rè kí Ó bù kún ọ ní ọ̀nà tó dára jù lọ fún Òun—àti pé láti fi ìfẹ́ Rẹ̀ hàn rè ní ojú ọ̀nà.
A lérò pé ó gbádùn ètò olọ́jọ́ márùn-ún onífọkànsìn lórí "Àwọn Ọ̀tá Ọkàn tí YouVersion látowó Andy. Túbọ̀ jìnlè àti ìmúniláradárẹ fún ìgbà pípẹ́títí àti ìmúpadàbọ̀sípò nípa gbígbà ìwé Andy, Àwọn Ọ̀tá Ọkàn, látowo àlaràtúntàa tó sún mọ́ ẹ.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.
More