Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ

Andy Stanley: Àwọn Ọ̀tá ọkàn
Ìfọkànsìn Ojọ́ Kẹrìn
“Sórà Fún Ojúkòkòrò ”
Ìwé Mímọ́: Lúùkù 12:13-21
Ọ̀tá ọkàn kẹtà? Ojúkòkòrò. Òun nígbà tí a bá ńímọ̀lára pé púpò àti púpò sí tí àwọn ọ̀rọ̀ àti ohun ayé yẹ wa. Ojúkòkòrò sọ wípé, “Mo je ara ní nǹkan.”
Jésù sọ pé, “Ẹ má ṣọ́ra! E máa se ẹ̀ṣọ́ lòdì sí ogbogbo onírúurú ojúkòkòrò.” Kí nìdí? Nítorí lára àwọn ipò ọkàn mẹ́rin tí a ń gbé yẹ̀ wò, ojúkòkòrò jẹ́ èyí tó àrékérekè jù lara gbogbo wón. Ojúkòkòrò lè bẹ̀rẹ̀ ìbùgbé nínú ọkàn ati gbé níbè fún ọdún láìmọ́. Ọkàn tí a kò sọ́ má tètè ko àrùn tó ń sọ ní di aláìlágbára. Ó le láti ṣàyẹ̀wò—pàápàá àyẹ̀wò fún ara ẹnì.
Jésù bá lò láti hù jáde ìró tó dáná gbogbo ojúkòkòrò: “Ayé kò sí ní eékún ohun ìní.” Àmọ́ ṣe gbogbo ènìyàn ló mò yẹn? Ṣé àwọn ènìyàn tiẹ̀ gbàgbó pé àwọn ayé wón dọ́gba sì ohun tí wọn ní? Ìdáhùn ní béèní àti béè kọ́. Ọtí, kìí se gbogbo ènìyàn ló mò yẹn. Àti bẹ́ẹ̀ní, àwọn ènìyàn wá tó gbàgbọ́ pé ayé rè jẹ́ àpapọ̀ gbogbo ohun tí ó ní. Àti pé òpò lára wa lónìí jẹ́ ìtẹ̀sí tún wà láti gbà èyí gbó jù bí a tí lè lérò lọ.
Lẹ́yìn ìgbà tó sọ òwe àkàwé, Jẹ́sù fún ìtumọ̀ ẹni tí olọ́júkòkòrò jẹ́: ẹnì tó tọjú àwọn ohun fún ara rè àmọ́ kò lọwọ́ síhà Ọlọ́run. Jíjẹ “Olówọ́ síhà Ọlọ́run” ní ọ̀rọ̀ - Jésù fún jíjẹ óláwọ́ síhà àwọn tọ́ nílò. Olọ́júkòkòrò ènìyàn ni ọkùnrin tàbí obìnrin tó ṣọ́ra pamó àmọ́ fúnni níwọ̀n bá díè.
Fífúnni ọ̀làwọ́ máa tú agbára ojúkòkòrò ká lórí ayé rè. Nígbà náà bóyá tàbí kò ó rò pé ó ní tó ṣekú, fúnni àti fúnni ní ọ̀nà ọ́làwọ́. Ó ní láti fúnni débi pé ó ṣe dandan fún ọ láti tún ìgbésí ayé rè ṣé. Tí ó kò bá ṣe tàn láti fúnni débi pé ó ni ipá lórí ìgbé ayé rè, nígbà náà níbamú sí Jésù, ó jé olọ́júkòkòrò. Tí ó mbá jẹ ùn débi pé díè lọ́ku tàbí kò sí ohunkóhun tó kù láti fúnni, ó jé olọ́júkòkòrò.Tí ó mbá jẹ́ ùn àti pamó débi pé díè lọ́ku tàbí kò sí ohunkóhun tó kù láti fúnni, ó jé olọ́júkòkòrò.
Mo mò pé ìyen lágbára. Gan-an, o gbóná.
Àmọ́ òtítọ́ ni.
Tú agbára ojúkòkòrò ká nípasẹ̀ ìwà ìfúnni ọlọ́làwọ́. Ó jé ìwà tó yí ohun gbogbo padà.
Sàyèwò ìwà olàwọ́ rè nínú fífúnni ni osù méjìlá tó kọjá. Kí ni ìwà fífúnni àánú rè sò nípa ọkàn rè? Gbàdúrà nípa ohun tí ó lè dàbí fún ọ láti gbé e wọnú ìpèle tún tún ní ìfúnni ọ́làwọ́ ni oṣù méjìlá tó ń mbò.
PoÌwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.
More