Àwon Òtá OkànÀpẹrẹ

Enemies Of The Heart

Ọjọ́ 3 nínú 5

Andy Staney: Àwọn ọ̀tá ọkàn náà<

Ètò ti Ọjọ́ kẹ́ta

“ Jíjọ̀wó̩ ọgbẹ́ àti ìbínú sílẹ̀

Ibi kíkà: Efeesu 4:25-32

ọ̀tá kejì tí ọkàn n naa ni ìbínú. A máa. n bí nú nígbà tí a ò bá rí ohun tí à ń fẹ́ gbà.

Fi oníbinú ènìyàn kan hàn mí un o sì fi ẹni ti a ti ṣa lọgbẹ́ ọkán hàn ọ́. Mo sì mú dáọ lójú pé a ti gba ohun kan lọ́wó̩ rẹ̀. Ẹnikan ń jẹ wọ́n ní gbèsè n kankan.

A sì mọ̀ àwọn eìyàn kan tí wọ́n le fi ìbínu wọn hàn ni ọ̀kan nínú àwọn ọ̀nà wọ̀n yí:"O jí ìjókọ mi lọ." "O jí ẹbí mi gbé. "Ọdún ayé mi tí ó dára jù ni o gbè lọ. "O jí ìgbéyàó mi gbé." " O fi àkókò ọ̀dọ́ mi dùn mí." "O lọ́ ìbálé mi gbà mọ́ mi lọ́wó̩.." "O jẹ mí ní ìlékún owó." "O jẹ mí ní ànfàní à ti gbìyànjú." “ O jẹ mí ní ànfàní à ti gbìyànjú lẹ́ẹ̀kejì si." “ O jẹ mí ní fífi ìfé̩hàn."

Gbòngbò ìbínú ni níní érò wípè ohun kan ti di mí mú lọ. Ohun kan ni a ń jẹ ọ́.Ní báyìí ìbáṣepọ̀ láàrín gbèsè àti ajẹgbèsè ti fo jú hàn kedere.

Ìwọ ń kó̩? Igbèsè wo ló n fa ìbínú fún ọ?

Fún ígbàwo ni o fi gbà láààyè kí àwọn tí ó ṣá ọ lọ́gbẹ́ fi darí ayé rẹ? Fún Oṣù kan? Fún ọdún miràn? Fún ìgbà ayérẹ míràn? Fún ìgbà wo?

Mo fẹ́ dábá rẹ̀ péòní ni kí ó jé̩ ọjọ́ tí ìwọ yóò fi ìpalára yìí sílẹ̀!

Bí ó ti e jẹ́ pé. o kō lè yí ọwọ́ aago sé̩yìn. Ó jẹ́ òtítọ́ bákan náà pè o kò gbọdọ̀ jé̩kí ìà àtijọ́ darí ọjọ́ iwájú rẹ. Nínú ìwé Efesù Kẹ́rin, a paáláṣẹ láti “ mu Gbogbo ìwà kíkorò àti ìbínú, àti ìrunú, kúrò." A lè ṣe eléyìí nípa " dídá ríji ara wa, bí Jesu ṣe dárí jì ó̩."

Ìwòsàn ìbínú ni ìdáríjì. tí a bá fojú ṣọ́nà láti gbẹ̀san nítorí ohun āìtọ́ tí a ṣe sí wa, àwa ni a ó san ẹ̀an. Ní ìdàkejì té a bá fagilé àwọn gbèsè tí a jẹ wá, a ó gba òmìnira.

Nínú gbogbo ipá mé̩rẹ̀ẹ̀rin ti a ń ṣẹ àgbéyẹ̀wò nínú ètòyii, Mo ní ìgbàgbọ́ pé èyí- ìbínú tí kò lójú tùú láti inú ogbẹ́ àmọ̀ó̩mọ̀ tàbí aìmọ̀ó̩mọ̀-òun ló burú jù. Níọnà míràn ẹ̀wẹ̀ òun ni ó rọrùn jù láti borí. O nílò láti pinnu nénú ọkàn tẹ láti fagolé gbèsè náà. O innu O sì wíi, "O kò jẹ mí ní gbèsè ohun kan mó̩."

Tẹ̀lé Ìlànà mé̩rin yìí lónìí. (1) Ṣe àwárí ẹni tí o ń bínú sí. (2) Ṣe ìṣúná ohun ti wọ̀n jẹ ọ́. (3) Fagilé gbèsè náà nípa dídáríjì wó̩n. (4) Máṣe jẹ́kí ìbínú yìí gbilẹ̀ mọ́.

Ìwé mímọ́

Day 2Day 4

Nípa Ìpèsè yìí

Enemies Of The Heart

Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Andy Stanley àti Multnomah fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: bit.ly/2gNB92i