Ìhámọ́ra Ọlọ́runÀpẹrẹ

Ọmọ ogun Róòmù “di abẹ́nú rè lámùrè” pẹ̀lú nǹkan tó fárajo àmùrè jù bẹ́líìtì lo. (Èyí tó jẹ́ ti ọkùnrin, O dámi lójú.) Ọ̀pọ̀ jù lọ ọ̀mọ̀wé akẹ́kọ̀ọ́jinlẹ̀ gbà pé ju ohunkóhun mìíràn lọ apá aṣọ ọmọ ogun tàbí ohun èlò, àmùrè yìí —pẹ̀lú onírúuru ìselóge e àti àwọn bẹ́líìtì gàgàrà—fi ìyàtọ̀ sáàárín omo ogun àti àwọn aráàlú. kìí se èròjà èyí tí ó wu ni, tí kò fi bẹ́ẹ̀ se pàtàkì, bí irú èyí tí èmi àti ìwọ le fi kún aso òde wa. O jẹ táṣìírí ète, lájorí kọ́kọ́ pàtàkì aṣọ rè. Ronú nípa èyíkéyìí àwọn àgbékọ́ amáraró ìbàdí tí àwọn òṣìṣẹ́ UPS® àti FedEx® ń wò tó yí ìsàlẹ̀ ẹ̀yìn wọn ká nígbà tí wọ́n ń bá gbẹ́rù tó wúwo.
A se àmùrè aláwọ tí omo ogun Róòmù ko dúró sán-ún, awọ tí omo ogun Róòmù láti dé ibi ara àti pèsè àtìlẹ́yìn tó se pàtàkì bí o ń se ìsúnlọsúnbọ̀ to yára, tí ni láti se níwájú ogun.
Òtító ni àtìẹ́yìn rè. O pèsè àtìlẹ́yìn tó se pàtàkì tí o nílò nígbà tí o bá wà láàárín ogun tẹ́mí.
Rántí, ohun èlò ti ọ̀tá gbìn sí wa lọ́kàn ni ẹ̀tàn. O bò òtítọ́ ní ibòji pẹ̀lú àwọn àwọ̀ mèremère tó ń fani mọ́ra ati ré ẹnì, tàn wa kúrò ní ìlànà dúdú àti funfun. O tàn ìrònú-asán kálè, tí ń fà àwọn ohun ara àti ti kò se pàtàkì láti fara hàn bákan bí ohun arabarìbì tó seyebíye àti rí ojú rere.
Ẹrù rè jẹ́ ogbọ́n bérébéré tó jẹ́ pé àyàfi tí a bá mò ohun tí ń se òtítọ́—mo túmọ̀ sí pé a mò o gidigidi gan, a mò látòkèdélẹ̀—yóò rọrùn fún wa láti ṣubú sínú pánpé rè.
Òtító —èyí tí a lè sàlàyé gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run lórí ọ̀rọ̀ tó ń sọ —òun ni ìlànà ww. Òtítọ́ ni eni ti Ọlọ́run jẹ́ àti ohun ti O so pé o jé, èyí tí a lè sàkópọ̀ e lọ́nà tó dára jù lọ fún wa nínú Ẹnì Jésù Kristi. Òtítọ́ Ọlọ́run. Òtítọ́ Bíbélì. Láìsí àdúrótì to jinlè àti ìdálójú pèlú òtítọ́ yìí —pèlú ojúlówó òtítọ́ —ó tán e lókun àti jẹ́ kí sí àwọn ohun tó lè dá bí pé won tóótun àti pé ìrọ́ awon tóótun síbè pàápàá won kò tóótun tètè ràn e. Àmọ́ pèlú ìlànà òtítọ́ tó wà níbi tó ye kọ́ wà, o lè sátúntó gbogbo nnkan mìíràn nínú ayé e— àwọn ìlépa rè, awon yíyàn rè, àwọn ìmọ̀lára rè; iyè inú rè, ìfẹ́ rè, àti àwọn èrò ìmọ̀lára rè—títí di ìgbà tí gbogbo nǹkan má fi tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ lónà títọ́. Nígbà tí o bá ní, fidi múlè, àtilẹ́yìn àárín dáadáa, kò ni rọrùn fún o láti ṣáko lọ nípa àwọn irọ́ ẹ̀tàn ọ̀tá. Di ara rè lámùrè pẹ̀lú òtítọ́, àti pé yóò wà ní olùṣọ́ fún ó̩ró̩gbólóhùn “lọ.”
Ojúlówó ìdánrawò máa wá nígbà tí àwọn èrò ọpọlọ àti àwọn ìmọ̀ ọgbọ́n orí tí àṣà wa bé sí òdìkejì, àti pé síbè a yàn láti dúró gbọn-in gbọn-in àti fìdi múlè lórí ìlànà Ọlọ́run ti kò yí padà. Àkókò náà tí dé fún wa láti je obìnrin tí a di ní àmùrè ni òtítọ́.

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Ní gbogbo ọjọ́, lójoojúmó, àwọn ogun àìrí njà ní àyíká rẹ - àìrí, àìgbọ́, sùgbón o ń ríi ipà rẹ ẹ̀ ní gbogbo ọ̀nà nínú ayé è rẹ. Àwọn ọmọ ogun èṣù ńwá ònà láti ṣe búburú nínú gbogbo ohun tí ó ṣe pàtàkì ṣí ọ: ọkàn rẹ, èèrò rẹ, ìgbéyàwó rẹ ẹ, àwọn ọmọ rẹ, àwọn ìbáṣepọ̀ rẹ, àwọn ohun tí o nla kàkà fún, àlá à rẹ, ọjọ́ iwájú rẹ̀ ẹ. Sùgbón èrò ìjà a rẹ dúró lóri pé kí ó ká ọ mọ́ láì ro àti lái gbaradi. Bí àtì kiri yìí àti bí ó ṣe ká ọ mọ́ láì gbaradi yìí bá ti su o, ètò yìí wà fún ọ. Ọ̀tá yìí má n kùnà pátápátá tí ó bá pàdé Obìnrín tí o gbaradi. Ìhámọ́ra Ọlọrun ju àlàyé Bíbélì lásán nípa ohun èlò tí onígbagbọ ní, o jẹ́ ohun tí a gbọ́dọ̀ ṣe láti wọ̀ ọ́, àti kíkọ́ ọna bi a o se yori funrarawa.
More
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Priscilla Shirer àti ẹgbẹ́ ẹ Lifeway Christian Resources fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí: www.lifeway.com