Gbogbo Ǹkan Tí Mo NílòÀpẹrẹ
Lópò ìgbà tí mo bá rò pé mo fé tàbí nílo nńkan títún ní ayé mi gidigidi, ohun tí mọ ń pòùngbẹ fún gan ní ìwàláàyè Olórun, ohùn Olórun, àti òrò Olórun. Níwájú Rè, ẹrù máa ń sá jù àwọn alàngbà kékeré tó máa ń wa lójú ònà ẹlẹ́sẹ̀ Gúúsù Florida lo àlàáfíà bo e bí Aṣọ ìbora òtútù lójọ́ yìnyín, àwọn ìlépa máa kún fún ìdùnnú títún.
Àwọn ìlépa tí a kò mò pé wọn mbè nínú ọkàn wa.
Níwájú Rè, a máa lálàá ní àwọn ònà títún. A má bá ọkàn É mu nítorí O n gbé nínú ọkàn wa Ọ sí yí wà pàdà láti inú wà. A mò ìdí ìwàláàyè wa láti inú Òtítọ Òrò Rẹ. Níwájú Rè, gbogbo ohun ti a lè ṣe àìní é má kàn kún àkúnya ní gbogbo ìgbé ayé wa. Nínú àkúnwọsílè yìí a máa ṣèdá pèlú Ọ̀gá Olúsèdá, àti ń Òun náà yóò ṣèdá nípasẹ wa.
Ìgbà gbogbo àti títí ní O máa ń mọ àwọn ohun títún látinú ti àtijọ́ àti àwọn ibi gbígbe nínú ayé e. Ọlọ́run kò kàn ní yi àwọn ìṣòro àti ogun é pada, àmó O ma kọ àwọn ìtàn TÍTÚN, àwọn àkọ́sórí TÍTÚN, àti àwọn ìdáwọ́lé TÍTÚN.
Ìwàláàyè Ọlórun máa mú àwọn ohun tó ti fọ́ dì odindi. Kìí ṣe nítorí nńkan kan ti a tí se, àmó nítorí Òun jé odindi. Òun jé àìlálàfo; Òun kìí bàjẹ́. Òun kìí se ìyapa tàbí rúdurùdu; Òun kìí ní ògbé tàbí ìdíbàjẹ́. Òun kìí ní egbò; Òun jé pípé. Òun kìí palára. Òun ní èmí ìyèkooro.
Àti nípasẹ Jésù Kristi, a jé odindi. A ti mú wa lára dà níwájú E.
Kò sí ohun bi ifagbára mú níwájú Rè ní ìlépa ìpín wa nípasẹ E. Kò sí ohun tó dá bí lilépa Olúpèsè.
Lépa Olúpèsè rè pèlú ìyìn àti ìdúpé, pèlú ìjọsìn, àtí pèlú òtítọ Òrò Rẹ̀.
Àtìpé má ṣe gbìyànjú nígbà gbogbo láti lépa fún ará é kódà nígbà tí o bá nira tàbí tíni lójú. Má ṣe fún ìfé ọkàn láti fà séyìn sí ìtùnú ìparọ́rọ́ lórí àga ibùsùn e láyè (tàbí pèlú òfifo tó ń tẹ lé wíwò Netflix). Níbití ẹni méjì tàbí mẹ́ta ba kó ara wọn jọ ni orúkọ mi, Olórun tí ṣèlérí láti wà níbè. Mo ti rí àwọn iṣẹ́ ìyanu alágbára to ń yá lénu nínú àwọn ọkàn àti ará àwọn tó wà Olórun papò… Mo ti rí àwọn iselè nínú ayé mi. Darapọ̀ mọ àwùjọ kan ki o sí wà níbè. Bí a tí dá wa láti dàgbà rẹ.
Kéde pé Ọlọrun ní Olórun lórí gbogbo àsìkò tó dára àti èyí tí kò dára, nígbà èèrùn àti nígbà èso bákan náà, àti àwọn àsìkò isé síse àti tí ìsimi. O fé gbò wa kéde òtítọ́, nítorí òtítọ É dára o sí lókun. Nígbà tí a bá sọ òtítọ, a rí ìdùnnú a sí dì moore. O fé ìdúpé wa, ìyìn wa, àti ìjọsìn wa nítorí O mò pé o máa ràn wá létí pé Òun mbè lórí ìté Òun sí tí lọ ṣáájú gbogbo nńkan ti a ń la kọjá lónìí.
Ọkàn mi ń lù kìkì fún é jù ohunkóhun lọ, ìwò tón kà àwọn òrò wonyìí. Mo fé jé kí o mò O, àti gẹ́gẹ́ bí O ṣe dára si. Kìí fí wa sílè kí a wa fúnra wa, Kìí jókòó fẹ̀yìntì kí O wò wa máa gbọ́ bùkátà ará wa fúnra wa tí a bá béèrè ìrànwọ́ látówó E.
O ti ṣèlérí fún wa pé tí a bá wa Òun, a máa rí Òun. Láìka ìbí ti a wa, àti bí a ṣe dé bè, Olórun ní ìpín pípé tón dúró dé.
Ọ̀rọ̀ Ìparí Láti Ronú Lórí Ati Ádùrá
Olórun, gbogbo èbùn réré àti ẹbùn pípé wà láti odò Yín, a ko lè tiè lóye ohun tí É ni nípamó ifún wa lójó iwájú… àmó a mo pé É tí fí dájú tẹ́lẹ̀, É tí sanwó e tẹ́lẹ̀, É ti té ipá ọnà fún wa láti wọlé.
Olórun, a fé wà níbí tí É wa. A fé rí ojú Yín, a fé gbo ohùn Yín, láti wà níwaju Ìfé pípé. Ìfé aláìlẹ́gbin, ìfẹé mímọ́gaara bí ekún ọmọ ìkókó.
É pàdé ẹní tó kà ètò yìí lówólówó níbí tí o wá lásìkò yìí, nítorí É mò o pátápátá. É mò àwọn ìlàkàkà e, àwọn ògùn t jà, àwọn aíìṣeyọrí, òkè tí wón là kọjá. É mò ohun tó nílò láti borí, àtìpé É ní nńkan náà ní ipàmò. Jù àwọn ẹbùn réré tí É mú wá fún wa gbogbo, É mú ìwàláàyè Yín to wa wà nísìsiyìí.
Nínú pákáǹleke, nínú òkùnkùn, nínú ìjà, nínú aginjù, a kò ní dẹkùn láti máa yìn Yín, kí a máa sìn Yín, kí a kígbe si Yín, gbékèlé Yín, a rẹ ará wa sílè níwájú Yín, a ń rántí bí É tí dé fi ìṣòtítọ́ mú wa dèbí.
A ń dúró ní ìrètí fún Yín, O Olúwa. Ìwọ ní ìpín wa tó jé pípé. Ìwọ ní gbogbo nńkan ti a nílò.
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run ti lọ ṣáájú wa ó sì ń pa wá mọ́ ní ọwọ́ ẹ̀yìn. Gbogbo ìdojúkọ wa ló ti yanjú. Gbogbo àlàfo ìdojúkọ ló sì ti dí pẹ̀lú. Ìpèníjà kò lè dé bá a lójijì. Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì ọlọ́jọ́-mẹ́ta yìí ma gbà ẹ́ ní ìyànjú nípa òtítọ́ wípé Ọlọ́run ni Olùpèsè ohun tó tọ́, àti èyí tó yẹ, fún ìgbésí ayé rẹ.
More