Gbogbo Ǹkan Tí Mo NílòÀpẹrẹ
Nítorípé Olórun ti síwájú wa, Ó sì fi ààbò Rẹ̀ bòwa lẹhin, Óún ni olùgbèjà wa nínú gbogbo ogun tí o bá dojúkọwá. Òun ló ñdí ogun níbi tí a kò fojúsí. Ko sì sí ohun tí ó lè jē ìyànú fún nípa ibi tí òtá le gbà yọ síwa. Bí a ṣe ñgbìyànjú láti síwájú Rẹ̀ nínú ogun, bẹẹ ní ààrẹ ńmúwa àti láti jà pẹ̀lú. Òun síwájú wa Ó sì fi déédéé ìwọ̀n ìgbàlà tí a nilo fún wa.
Kòsí ohun tó jù ìpín tí Ó yàn fún ìgbé ayé wa, nítorípé ìpín tí Olórun tí yàn fún wa jé tiwa ati àwa nìkan. Ìpín wa yíò pèsè odindi àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkán fún wa, sùgbón kìí ṣe fún àwọn ẹnìkejì wa. Bákannáà, ìpín tí àwọn ẹnìkejì wa kò jẹ́ dandan láti dàbí tiwa tàbí kí o fara jọ irú èyí tí a nílò. Olórun ní ò lè ṣe ìdíwọ̀n ìpín tí ó péye fún wa láti jí gìrì ka dì wà láàyè ní kíkún
Ìfẹ́ Ọlọrun ní láti fún wa ní ìpín Rẹ̀ fún ìgbé ayé wa. Ko mọ́ lara lati fa ọwọ ẹbùn Rè fúnwa sẹ́yìn. Ohun tí Ó fẹ ní láti mú wọn wà ní pípé. Bí a bá béèrè àkàrà lọwọ Rẹ̀ kò ní fúnwa ní òkúta.... nitorina béèrè! Kò lè dúró dèwa láti jẹ ìgbádùn ìpín náà, ìwọ̀n tí ó jẹ iyalẹnu ati alailẹgbẹ fúnwa.
.Sáà má béèrè pẹlu èrò tí ó tí ní nínú rẹ̀ nípa ohun tí ìpín yẹ jẹ.
.Nígbàtí á ba síwájú Ọlọrun tí á sí ṣe agbekalẹ àlà àti ìpinnu wa laijẹ kí Ọlọrun mọ sí ní á máa mbá arawa ninu ijakule tí o lágbára.
Ẹ jékí á rántí lóni Òun ní ìpín wa. Ó ní ìdíwọ̀n ẹbùn tí á tí fí ìtara ati ìrora rà fúnwa. Jésù Kristi ṣiṣẹ fúnwa. Ó laagun fúnwa. Ó farada fúnwa. Ó tá ẹjẹ Rẹ silẹ fúnwa. Ó sì kú fúnwa pẹlu. Sùgbón ní pàtàkì jùlọ kò gbé gbogbo ogun wá sí ejika Rẹ̀ fúnwa, Ó ṣẹgun fúnwa nikọkan ohun tí ó ńdunkoko mọ́wa kí á baale gbé ìgbé ayé kíkún.
Àtipé gbogbo ọrọ wọnyi nípa ìpín nmuki ebi pamí. Mo fé ló wá nkán jẹ.
Ìwòye.
Nípa Ìpèsè yìí
Ọlọ́run ti lọ ṣáájú wa ó sì ń pa wá mọ́ ní ọwọ́ ẹ̀yìn. Gbogbo ìdojúkọ wa ló ti yanjú. Gbogbo àlàfo ìdojúkọ ló sì ti dí pẹ̀lú. Ìpèníjà kò lè dé bá a lójijì. Ẹ̀kọ́ Àṣàrò Bíbélì ọlọ́jọ́-mẹ́ta yìí ma gbà ẹ́ ní ìyànjú nípa òtítọ́ wípé Ọlọ́run ni Olùpèsè ohun tó tọ́, àti èyí tó yẹ, fún ìgbésí ayé rẹ.
More