Bí A Ti Lè Bẹ̀rẹ̀ Sí Ní Ka BíbélìÀpẹrẹ
Kíkọ́ Láti Gbẹ́kèlé Ọlọ́run Nípasẹ Ọ̀rọ̀ Rẹ̀
Láti Gbékèlé Olórun nínú ìmólè kìí ṣe nǹkan nǹkan. Àmó láti gbékèlé nínú òkùnkùn, èyí ní ìgbàgbọ́. — Charles Spurgeon
Sisé àṣà Bíbélì kíkà òjòójùmo àti kikó láti lọ òtítọ máa àjọṣe tímọ́tímọ́ wa pèlú Olórun pò sí títíláé. Àmó nígbà mìíràn, bóyá lópò ìgbà, o lè dá bí pé Bíbélì kò fọhùn. o lè dàbí kò pápò pèlú ohun tí a ń la kọjá nínú ayé wa. Àtìpó tí a bá jé olóòótọ , kìí ṣe ìgbà gbogbo lọ n máa dá bí pé Olórun dára nítorí Kìí fún wa ní ohun tí a bá fé tàbí béèrè fún.
Nípa tíèsíwájú sínú òrò Olórun, a máa rí pé àwọn ètò Rè dára àti pé O ní anfààní wa okùn ọkàn pípé Rè. Àmó, èyí tó dára jù Rè, kìí se èyí tó dára jù t'awa. O rí ohun táwa ò rí àti mò ohun tí a nílò àti ìgbà tí a nílò rè. Gbigbékèlé Olórun séle nígbà tí a bá mò ení Tó jé.
Kíkà àti lilọ òrò Olórun sí ayé wa máa ràn wá lọ́wọ́ láti túbọ̀ gbékèlé E lójòójùmo Olórun ń se òtítọ sí àwọn ìlérí Rẹ̀. O ń ṣe òpò ìlérí sí wa nínú Bíbélì tó fi ìrètí sínú wa nígbà tí a bá gbà wón, àmó é jé kí a wò díè lára wọn. Olórun ṣèlérí pé…
... Tí a bá jéwó àwọn àìsédédé , Òun yóò d'áríjì wa àti fò wa mò.(1 Jóhànù 1:9)
... tí a bá tò wá nígbà ààrẹ wa, Òun yóò fún wa ní ìsimi. (Mátíù 11:28-29)
... tí a bá tèlé E, a kò ní rìn nínú òkùnkùn láé . (Jòhánù 8:12)
... tí a bá dúró níbẹ̀ Rè,a máa síso èso púpọ̀. (Jóhànù 15:5)
... tí a bá ṣe àìní ọgbón, O fúnni lónà ọ̀làwọ́. (Jákòbù 1:5)
... tií a bá gbàgbó àti jéwó pé Jésù ní Olúwa, a yóò gbà wa là . (Róòmù 10:9)
Àwọn nǹkan máa wá ti a má kà tí kò ní mú ọpọlọ wa tàbí kódà o ṣeé ṣe tún tojú sú u wa, àmó bí Wòlíì Andy Stanley ṣe sò, “O kò ní láti lóyè gbogbo e láti gbàgbó nínú nǹkan.” Bí a ń se túbò wà A sí, ní a má máa mò O sí. Àti bí a ń se túbò mò O sí, ní a ń se túbò gbékèlé É sí. Nígbà tí a bá sódì isé òjò wa, nígbà yen ní a máa bá mò O gégé bí olùdaríìl ìpà ònà wa, ení tí ń fúnni lógbón , ìtùnú ẹni tí ń mú ìtùnú wà, ẹni tó ń pèsè ìrètí, àti ẹní tí ń olùpèsè àlàáfíà.
Ronú wòye
- Ṣe o gbékèlé Olórun àti òrò Rè? Kíni ohun tó ń fà o sèyìn láti gbékèlé E?
- Lọ àkókò díẹ̀ ní sísọ àwọn ẹdun ọkàn rè àti àwon ìbẹrù rè sí Olórun. O mò wón tèlé, torí náà má ṣe fà séyìn. Léyìn náà, béèrè lówó Rè láti ràn é lówó láti gbékèlé É pèlú gbogbo ohun tó ń mú o rèwè sí
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Lòótọ́, a mọ̀ pé kíka Bíbélì dára, ṣùgbọ́n ó le ṣòro láti mọ ibi tí a ti le bẹ̀rẹ̀. Ní ọjọ́ mẹrin tó ń bọ̀, a ó máa kọ nípa ìdí tí Bíbélì fi ṣe pàtàkì, bí a ṣe le bẹ̀rẹ̀ ìwà ìwé-kíka ojoojúmọ́, àti bí a ṣe lè lò ní ayé wa ti òní.
More