Àwọn Ìṣé ÌrònúpìwàdàÀpẹrẹ

Acts of Repentance

Ọjọ́ 1 nínú 5

Orin Dáfídì 51 jẹ́ igbe Dáfídì sí Ọlọ́run fún ìdáríjì kúrò nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tó dá ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé lẹ́yìn àṣemáṣe rẹ̀ pẹ̀lú Bátṣèbà. Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ lè fojú inú rí Dáfídì lórí orúnkún rẹ̀ tó ń kígbe pe Ọlọ́run lóhùn rara wípé kí ó wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ òhun kúrò. Orin Dáfídì yìí fún wa ní àwòrán bí ìrònúpìwàdà ṣe yẹ kí ó rí nínú ayé wa. Lákọ̀ọ́kọ́, Dáfídì gbà wípé òhun ṣẹ̀. Lẹ́hìn náà, ó tọrọ ìdáríjì. Lẹ́hìn èyí, ó ní kí Ọlọ́run sọ òhun di ọ̀tun. Lákòótán, ó ní kí Ọlọ́run ran òhun lọ́wọ́ láti fi ẹ̀ṣẹ̀ òhun kọ́ àwọn tí ó wà nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n sì nílò ìrònúpìwàdà ní ẹ̀kọ́. Kínni ìrònúpìwàdà jọ nínú ayé tìrẹ? Báwo ni àpẹẹrẹ ìrònúpìwàdà Dáfídì ṣe le mú kí ìbáṣepọ̀ rẹ pẹ̀lú Ọlọ́run kó nípọn ṣí?

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Acts of Repentance

Ìrònúpìwàdà jẹ́ ọ̀kan lára ìgbésẹ̀ tó ṣe kókó tí à ń gbé láti mọ Krístì ní Olùgbàlà wa. Ìrònúpìwàdà ni ojúṣe wa, Ìdáríjì sì ni èsì Ọlọ́run sí wa láti inú ìfẹ́ pípé tí ó ní sí wa. Lásìkò ètò ọlọ́jọ́ márùún yìí, wàá gba bí...

More

We would like to thank Life.Church for providing this plan. For more information, please visit: www.life.church

YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa