Mú Ẹ̀rù Kúrò Lọ́nàÀpẹrẹ

Get Rid Of Fear

Ọjọ́ 2 nínú 3

Kíni ìwo yio sé nígbàtí èrò okàn ré bá fá ìbèrù tí ó l'agbára sí o l'ókàn?

Ìwé Mímó fíyewá pé oógun tí ó kápá ìbèrùbojo àti aníyàn ní àdúrà jé. Láti mò bí àdúrà sé l'agbára tó àti ohun tí ó lèse lórí èrù bíbà, e jékí á wo ìwé Fílípì 4:6-7. Èsè kefà wí báyi pé " Kì á má sé aníyàn nítorí ohúnkohún, sùgbón nínú ohungbogbo pèlú àdúrà àti èbè pèlú ìdúpé jékí ìbèrè ré dí mímò fún Olórun"

Nígbàkúgbà tí èrù bá nbá wà, e jékí á tètè fí òtító òrò Olórun kó lí ojú, Olórun so nínú òrò Re pé á ní láti sé àyídà rè nítorípé enikéni tàbí ohúnkohún tó bá sé adarí okàn wa, ní ó jé olùdarí wà. Olórun kò fé kí á fí okàn wa sí ohun tí ó lé mú ìbèrù wá sí ókàn wà, kí wón sí jé olùdarí wá. Bíkòsepé, kí á fí èrò okàn wá gbogbo sí òdò Rè kí á sí jékí òrò àti Èmí Rè sé olùdarí wa. Ìdí nìyí tí àdúrà sé jé pàtàkì. Àgbékalè yí sí rorùn fún wa. Máse bèrù ohunkóhun, sùgbón gbá àdúrà nípa ohun gbogbo

Fílípì 4:6 sé àgbékálè òrò tí á lè lo fún àdúrà àti fun èbè, tí ó ntóka wa sí ìbèrè fun ohun kan pàtó.Tí á bá ní èrù l'ókàn wa sùgbón tí á kò lè so ní pàtó ohun tí ó sé ókùnfà rè, e jékí á mú to Olúwa lo nínú àdúrà-Ó mo bi ó sé jé. Tàbí tí á bá mo ohun kan pàtó tí ó fá ìbèrù tí ó sí da wa lójú ní okàn wa, e jékí á mú to Olórun lo pèlú. Bēre lówó Rè fún ìrànlówó láti mú ìbèrù kúrò kí ó sí fí òtító òrò Rè dípò, kí á sí fí ìgbàgbó dúpé fún ohun tí ó sé fún wa

Olúwa oloore òfé, àparò méjì kò ní á tà ní òwó ìdè wéwé méjì bi? Síbè ó mò ohun gbogbo nípa wa. Ó sí mò íyè irun orí wà pèlú. Ran mí lówó kì ó sí fún mi ní ìgbóyà láti mó òrò ré nípa bi ó tí sé mò mi tí ó sí ní ìfé mi. Rán mi létí láti ònílo pé kí ñmáse bèrù nítorípé ohun gbogbo ní ó wà l'ábé àkóso Re. Ó sí tí s'èlérí láti má fimísílè tàbí kòmísílè. Mo dúpé fún àwon ìlérí wònyí tí ó sí fún mi ní àláfíà ní orúko Kristi. Àmín.

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 1Ọjọ́ 3

Nípa Ìpèsè yìí

Get Rid Of Fear

O lè borí ẹ̀rù. Dr. Tony Evans ma mú ẹ lọ́wọ́ dání ní ipa ọ̀nà sí òmìnira nínú ètò kíkà tó ní ìṣúra ọgbọ́n nínú yìí. Ṣàwarí ìgbé ayé aláyọ̀ àti tí àlàáfíà tí o ti ń pòǹgbẹ fún bí o ti ńṣe àmúlò àwọn ìlànà tí a gbé kalẹ̀ sínú ètò yí

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ilé-isẹ́ Harvest House Publishers fún ìpèsè ètò yí. Fún àlàyé síwájú síi jọ̀wọ́ lọ sí: http://go.tonyevans.org/addiction