Owe 8:12-14
Owe 8:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Èmi, ọgbọ́n ń gbé pẹ̀lú òye; mo ní ìmọ̀ àti ọgbọ́n-inú. Ìbẹ̀rù OLúWA ni ìkórìíra ibi mo kórìíra ìgbéraga àti agídí, ìwà ibi àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn. Ìmọ̀ràn àti ọgbọ́n tí ó yè kooro jẹ́ tèmi mo ní òye àti agbára.
Pín
Kà Owe 8Owe 8:12-14 Yoruba Bible (YCE)
Èmi, ọgbọ́n, òye ni mò ń bá gbélé, mo ṣe àwárí ìmọ̀ ati làákàyè. Ẹni tó bá bẹ̀rù OLUWA, yóo kórìíra ibi, mo kórìíra ìwà ìgbéraga, ọ̀nà ibi ati ọ̀rọ̀ ìbàjẹ́. Èmi ni mo ní ìmọ̀ràn ati ọgbọ́n tí ó yè kooro, mo sì ní òye ati agbára.
Pín
Kà Owe 8Owe 8:12-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi ọgbọ́n li o mba imoye gbe, emi ìmọ si ri imoye ironu. Ibẹ̀ru Oluwa ni ikorira ibi: irera, ati igberaga, ati ọ̀na ibi, ati ẹnu arekereke, ni mo korira. Temi ni ìmọ ati ọgbọ́n ti o yè: emi li oye, emi li agbara.
Pín
Kà Owe 8