Owe 8:12-14

Owe 8:12-14 YBCV

Emi ọgbọ́n li o mba imoye gbe, emi ìmọ si ri imoye ironu. Ibẹ̀ru Oluwa ni ikorira ibi: irera, ati igberaga, ati ọ̀na ibi, ati ẹnu arekereke, ni mo korira. Temi ni ìmọ ati ọgbọ́n ti o yè: emi li oye, emi li agbara.