Ọ̀kan nínú àwọn ọgbọ̀n (30) náà: Asaheli arákùnrin Joabu sì Jásí Elhanani ọmọ Dodo ti Bẹtilẹhẹmu; Ṣamma ará Haroditi, Elika ará Harodi. Helesi ará Palti, Ira ọmọ Ikẹsi ará Tekoa; Abieseri ará Anatoti, Sibekai ará Huṣati; Salmoni ará Ahohi, Maharai ará Netofa; Heledi ọmọ Baanah, ará Netofa, Ittai ọmọ Ribai to Gibeah ti àwọn ọmọ Benjamini; Benaiah ará Piratoni, Hiddai ti Àfonífojì Gaaṣi, Abi-Alboni ará Arbati, Asmafeti Barhumiti; Eliaba ará Ṣaalboni, àwọn ọmọ Jaṣeni, Jonatani; ọmọ Ṣamma ará Harari, Ahiamu ọmọ Ṣarari ará Harari; Elifeleti ọmọ Ahasbai, ọmọ ará Maakati, Eliamu ọmọ Ahitofeli ará Giloni; Hesro ará Karmeli, Paarai ará Arba; Igali ọmọ Natani ti Ṣoba, Bani ará Gadi; Seleki ará Ammoni, Naharai ará Beeroti, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Joabu ọmọ Seruiah; Ira ará Itri, Garebu ará Itri. Uriah ará Hiti.
Kà 2 Samuẹli 23
Feti si 2 Samuẹli 23
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: 2 Samuẹli 23:24-39
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò