II. Sam 23:24-39
II. Sam 23:24-39 Bibeli Mimọ (YBCV)
Asaheli arakunrin Joabu si jasi ọkan ninu awọn ọgbọ̀n na; Elhanani ọmọ Dodo ti Betlehemu. Ṣamma ara Harodi, Elika ara Harodi. Helesi ara Palti, Ira ọmọ Ikkeṣi ara Tekoa, Abieseri ara Anetoti, Mebunnai Huṣatiti, Salmoni Ahohiti, Maharai ara Netofa, Helebu ọmọ Baana, ara Netofa, Ittai ọmọ Ribai ti Gibea ti awọn ọmọ Benjamini, Benaia ara Piratoni, Hiddai ti afonifoji, Abialboni ara Arba Asmafeti Barhumiti, Eliahba ara Saalboni, Jaṣeni Gisoniti, Jonatani, Ṣamma Harariti, Ahiamu ọmọ Ṣarari Harariti, Elifeleti ọmọ Ahasbai, ọmọ ara Maakha, Eliamu ọmọ Ahitofeli ara Giloni, Hesrai ara Kermeli, Paari ara Arba, Igali ọmọ Natani ti Soba, Bani ara Gadi, Sekeli ara Ammoni, Nahari ara Beeroti, ẹniti o nru ihamọra Joabu ọmọ Seruia. Ira ara Jattiri, Garebu ara Jattiri. Uria ara Hitti: gbogbo wọn jẹ mẹtadilogoji.
II. Sam 23:24-39 Yoruba Bible (YCE)
Àwọn mìíràn tí wọ́n tún jẹ́ ara “Àwọn Ọgbọ̀n Akọni” náà nìwọ̀nyí: Asaheli arakunrin Joabu, ati Elihanani, ọmọ Dodo, ará Bẹtilẹhẹmu. Ṣama ati Elika, àwọn mejeeji jẹ́ ará Harodu; Helesi, ará Paliti, Ira, ọmọ Ikeṣi, ará Tekoa; Abieseri, ará Anatoti, ati Mebunai, ará Huṣa; Salimoni, ará Ahohi, ati Maharai, ará Netofa; Helebu, ọmọ Baana, tí òun náà jẹ́ ará Netofa, ati Itai, ọmọ Ribai, ará Gibea, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini; Bẹnaya ará Piratoni ati Hidai ará ẹ̀bá àwọn odò Gaaṣi; Abialiboni ará Araba, ati Asimafeti ará Bahurimu; Eliaba, ará Ṣaaliboni, àwọn ọmọ Jaṣeni, ati Jonatani; Ṣama, ará Harari, Ahiamu, ọmọ Ṣarari, ará Harari; Elifeleti, ọmọ Ahasibai, ará Maaka, Eliamu, ọmọ Ahitofẹli, ará Gilo; Hesiro, ará Kamẹli, Paarai, ará Abiti; Igali, ọmọ Natani, ará Soba, Bani, ará Gadi; Seleki, ará Amoni, Naharai, ará Beeroti, tí ó máa ń ru ihamọra Joabu, ọmọ Seruaya. Ira ati Garebu, àwọn mejeeji jẹ́ ará Itiri; ati Uraya, ará Hiti. Gbogbo àwọn tí wọ́n jẹ́ akọni ọmọ ogun náà jẹ́ mẹtadinlogoji.

II. Sam 23:24-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ọ̀kan nínú àwọn ọgbọ̀n (30) náà: Asaheli arákùnrin Joabu sì Jásí Elhanani ọmọ Dodo ti Bẹtilẹhẹmu; Ṣamma ará Haroditi, Elika ará Harodi. Helesi ará Palti, Ira ọmọ Ikẹsi ará Tekoa; Abieseri ará Anatoti, Sibekai ará Huṣati; Salmoni ará Ahohi, Maharai ará Netofa; Heledi ọmọ Baanah, ará Netofa, Ittai ọmọ Ribai to Gibeah ti àwọn ọmọ Benjamini; Benaiah ará Piratoni, Hiddai ti Àfonífojì Gaaṣi, Abi-Alboni ará Arbati, Asmafeti Barhumiti; Eliaba ará Ṣaalboni, àwọn ọmọ Jaṣeni, Jonatani; ọmọ Ṣamma ará Harari, Ahiamu ọmọ Ṣarari ará Harari; Elifeleti ọmọ Ahasbai, ọmọ ará Maakati, Eliamu ọmọ Ahitofeli ará Giloni; Hesro ará Karmeli, Paarai ará Arba; Igali ọmọ Natani ti Ṣoba, Bani ará Gadi; Seleki ará Ammoni, Naharai ará Beeroti, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Joabu ọmọ Seruiah; Ira ará Itri, Garebu ará Itri. Uriah ará Hiti.