KRONIKA KINNI 16:8-9

KRONIKA KINNI 16:8-9 YCE

Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA, ẹ képe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde ohun tí ó ti ṣe fún àwọn orílẹ̀-èdè. Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn sí i, ẹ sọ nípa àwọn ohun ìyanu tí ó ṣe!