1 Kronika 16:8-9

1 Kronika 16:8-9 YCB

Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nínú àwọn ènìyàn fún ohun tí ó ṣe Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn, sí i, Ẹ sọ ti gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀