I. Kro 16:8-9
I. Kro 16:8-9 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA, ẹ képe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde ohun tí ó ti ṣe fún àwọn orílẹ̀-èdè. Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn sí i, ẹ sọ nípa àwọn ohun ìyanu tí ó ṣe!
Pín
Kà I. Kro 16Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA, ẹ képe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde ohun tí ó ti ṣe fún àwọn orílẹ̀-èdè. Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn sí i, ẹ sọ nípa àwọn ohun ìyanu tí ó ṣe!