Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (May)Àpẹrẹ
Nípa Ìpèsè yìí
Apa karun ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá karun ní àwọn Iwé Korinti Kinni ati Ekeji, Diutaronomi, ati Josua.
More
We would like to thank Life.Church for providing this plan. For more information, please visit: www.life.church