Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (November)
Ọjọ́ 30
Apá kọkànlá a ti onipin mejila, ètò yí wà láti darí àwọn ẹgbẹ tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lapapọ ni ọjọ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ni gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí lè bá Bíbélì olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogún iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹlú ori Bíbélì láti inú májẹ̀mú àtijọ àti Majẹmu titun, pẹlú iwe Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá kọkànlá ní àwọn ìwé Orin Solomoni, Ìsíkíẹlì, Hosia, ati ìwé Ìfihàn.
A fẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ sí, jọwọ lọ sí: www.life.church
Nípa Akéde