Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (June)

Jẹ́ kí a ka Bíbélì papọ̀ (June)

Ọjọ́ 30

Apa kẹfà ti onipin mejila, ètò yìí wà láti darí àwọn egbé tàbí ọrẹ nínú gbogbo Bíbélì lápapọ̀ ní ọjọ́ 365. Pe àwọn mìíràn láti darapọ̀ mọ́ ọ ní gbogbo ìgbà tí o bá bèrè apá titun ní osoosu. Ìpín yìí le bá Bíbélì Olohun ṣiṣẹ - tẹtisilẹ ní bíi ogun iṣẹju lójoojúmó! Apá kọọkan wá pẹ̀lú orí Bíbélì láti inú Májẹ̀mú àtijọ́ àti Majẹmu titun, pẹ̀lú Ìwé Orin Dáfídì láàrin wọn. Apá kẹfà ní àwọn Iwé Efesu, Filipi, Kolose, Jona, Àwọn Adajọ, Rutu, àti Samueli kínní.

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé die síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church
Nípa Akéde