Ìgbé Àyè Kristeni, Ìgbé Ayé Ìrúbọ Àti iṣẹ ÌsìnÀpẹrẹ
Lo Ẹbùn Rẹ
Pa Oju rẹ dè kí o wò àwòrán ìjọ awọn eniyan ẹgbẹrun kan ni ipejọpọ gẹgẹbi gbogbo ará Kristi ti kó ni enikan to ni ẹbun.
Àbájáde rẹ yóò jẹ idarudapọ; aini ìtọ́sọ́nà, ailojútù ati ailájọṣiṣẹ́pọ̀, àìní tọpjú ati abojuto to péye ipejọpọ eniyan. Láàrin ẹsẹ 6- 7, atọka sí ẹbun méje ti a filè mọ ati ṣe abojuto ìjọ.
Ale má ri gbogbo ẹbun yi nínú gbogbo ijo kàn kàn ṣugbọn oyẹ kí a mọ pàtàkì awọn ẹbun yi àti kí a ni idapọ pẹlú àwọn ti Ọlọrun fi wọn fún.
Ẹbùn ibà wu kòní Ọlọrun fi fún ọ kí olè lọ fún imudagba ati ṣiṣe itọju ìjọ sí ògo Ọlọrun ati didari àwọn eniyan sí Kristi.
Kíka Siwaju sii: Éfésù 4, 1 Kọ́ríńtì 12:20-26
Adura: Ran mi lọwọ OLÚWA lati lò ẹbun òré ọfẹ rẹ nínú ayé mi, ma jẹki nṣi lo.
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Igbe Ayé Kristeni kii ṣe ìgbé Ayé irọrun, ọrọ àti itẹlọrun ní gbogbo ìgbà ṣugbọn ojẹ ìgbé Ayé Ìrúbọ ati ìsìn. Jésù wá sí ayé láti wá fi àpẹẹrẹ náà hàn fún wa láti ri. Jésù wá, o gbè ìgbé Ayé isẹrà ẹni, aimọtàrà ẹni nikan, iyasọtọ, iwọntunwọnsi ati ìrúbọ titi ti O fi kù fún ìràpadà wá. Ìdí yii ni àfi ni àkọsílẹ̀ rẹ ninú awọn ìwé ìhìnrere.
More
A yoo fẹ lati dupẹ lọwọ Adeoye Gideon fun ipese eto yii. Fun alaye diẹ sii, jọwọ ṣabẹwo: https://www.facebook.com/gideon.adeoye?mibextid=ZbWKwL